Notice: file_put_contents(): Write of 625 bytes failed with errno=28 No space left on device in /www/wwwroot/muzbon.net/system/url_helper.php on line 265
Agaga - Mo 40 (Remix) | Скачать MP3 бесплатно
Mo 40 (Remix)

Mo 40 (Remix)

Agaga

Альбом: Mo 40 (Remix)
Длительность: 2:45
Год: 2025
Скачать MP3

Текст песни

Kiloma njami laya nani 
Lẹyin ọrọ owo nani 
Agaga seasonman nani
Angẹli orin nani 

Mio lema lemu ngbo 
Kintuma lemu inu abọ
Timoti jagun timo tibọ
Wọn wa sọpe kinma fọ
Kinma fọ fun awọn wo
Kinma fọ fun awọn wo
Ani kin fọ fun awọn wo
Iyalalaya wọn loma fọbi awo
Iwọ mu henessy 
Emi mu chelsea
Ajọ mayo nani
Elelpd lo lulu abi Mr Dj
Ajọ majo nani 
You're born in America 
I'm born in Africa 
Ajọ gba visa aye nani 
Ojo rọ larọ Oorun rọ lọsan
Ilẹ maṣu nani 
Iwọ sọko fun emi gungi lọ
Ajọ majẹ cashew nani 
Ati ẹni lowo Ati ẹni ti kolowo
Gbogbo wa jọma ku nani 
Abi kila ngbe ta ngbin yeah yeah 

Eee Ajọma ee Ajọma ee Ajọma ee Ajọma ee Ajọma eeee
Eee Ajọma ee Ajọma ee Ajọma ee Ajọma ee Ajọma eeee
In the making Ajọma 
Ajọma lowo lọwọ ni 
Ajọma 
Breaking records 
Ajọma 
International deals 
Ajọma 
Multi million dollars 
Ajọma 
Winning contract 
Ajọma 

3 gboosa fun Agaga 
Ọba lamba otipọju 
3 gboosa fun Agaga 
Ọba lamba otipọju

Miolema lemu ninu street o
Kin tunma fagidi la sweet o
This country is a cheat ooo
Monkey dey work 
Baboon dey chop ooo
Batuni kagbe ẹjọ lọ court o
Gbogbo awọn adajọ 
Nati corrupt ooo
Kilẹ ngbe tẹngbin 
Ati ẹni to nfoloke 
Ati ẹni to nrin nilẹ
Ajọma dele nani 
Oṣe party opa maalu 
Emi pa ewurẹ
Ọbẹ matan nani 
Ojẹ pizza jẹ shawarma
Emi jẹ ẹwa agọnyin 
Ajọma so nani 
O' Graduate abi 
O drop out ni naija 
Akuṣi nwaṣẹ nani 
Illiterate ati literate kilanwa 
Atijẹ lanba kakiri 
Boya okọ fuji ni
Abi okọ hiphop 
Agbe lonṣe kakiri 
Civil servant tonlọṣe Dorime Dorime 
Oma pada tẹ nani 
Kolowo lọwọ koniṣẹ lọwọ
Olọn le oko  ibẹrẹ oriburuku nani

Oku ẹyọ kan oku ẹyọ kan 
Ẹwa nbi ẹmayi lọ
Ati oniṣẹ ọwọ 
Pẹlu awọn politicians 
Irọ oriburuku nani 

Haaaaaaaaaaaaaaaaa