Notice: file_put_contents(): Write of 632 bytes failed with errno=28 No space left on device in /www/wwwroot/muzbon.net/system/url_helper.php on line 265
Angélique Kidjo - Bahia | Скачать MP3 бесплатно
Bahia

Bahia

Angélique Kidjo

Альбом: Black Ivory Soul
Длительность: 3:34
Год: 2002
Скачать MP3

Текст песни

Aburo, orè ni gbogbowa, ewa ka lolé
Aburo, ibi kan ni wao, kamura si ifè
Didan ni ilé ti bahia
Ti émin mon wa, ri yin lénin o

Bahia, Bahia, Bahia
Bahia, Bahia, Bahia
Bahia, Bahia, Bahia
Bahia, Bahia, Bahia

(Ile aye) Ilé ti babawa jina, awa fè lolé (ile aye)
Bahia ilu ti awa leni, opè gan si ilé (ile aye)
Ogun ti awon agbalagba, se kalè fun wa o (ile aye)
Logbé wa lo si Bahia, gbé gbogbowa po

Bahia, Bahia, Bahia (oré ifé ayé yilé)
Bahia, Bahia, Bahia (oré ifé ayé yilé)
Bahia, Bahia, Bahia (oré ifé ayé yilé)
Bahia, Bahia, Bahia (oré ifé ayé yilé)

(Ile aye) ojo ipadé wa m'bowa o, ti ale rira wa (ile aye)
Ewa ka mura fojo yen ninu oyaya (ile aye)
Oluwa fun wa niyé o, ejè ka du kpè (ile aye)
Bahia pa gbogbowa po, iréti wa lona

Aburo, orè ni gbogbowa, ewa ka lolé
Aburo, ibi kan ni wa o kamura si ifè
Didan ni ilé ti bahia
Ti émi mu wa, ri yin léni o

(Oré ifé ayé yilé) Bahia, Bahia, Bahia
(Oré ifé ayé yilé) Bahia, Bahia, Bahia
(Oré ifé ayé yilé) Bahia, Bahia, Bahia
(Oré ifé ayé yilé) Bahia, Bahia, Bahia

Hmm, aburo, orè ni gbogbowa, ewa ka lolé (Bahia, Bahia, Bahia)
Aburo, ibi kan ni wao, kamura si ifè (Bahia, Bahia, Bahia)
Didan ni ilé ti bahia ti émi mon wa, ri yin léni o (Bahia, Bahia, Bahia)

(Oré ifé ayé yilé) Bahia, Bahia, Bahia
(Oré ifé ayé yilé) Bahia, Bahia, Bahia
(Oré ifé ayé yilé) Bahia, Bahia, Bahia
(Oré ifé ayé yilé) Bahia, Bahia, Bahia
Oré ifé ayé yilé