Konko Below (Not Responsible Version)
Segunspark
Igba o lọ bi orere Bo ba koro oṣi maa dun ah Eni to ni suuru kii ṣeyan kekere Bo ba kan lẹ oṣi maa goke ah Boo ba ṣe un tọ fe won maa kẹyin si e ẹh a ẹh Bo ba ṣe tirẹ o o ma jẹ ire fun ẹ Ọlanrewaju ọmọ ọba E ma suure da gba won ni ko o ṣe were roora ṣe E ma suure da gba oo Olooto ko ni ku si bi ọtẹ ooo Olanrewaju ọmọ mi E ma suure da gba oo Igba o lọ bi orere Bọmọde oku oo oṣi maa da gba Ṣọra funja ṣọ ra fẹgbẹkẹgbẹ Oun tio to o oṣi maa pọ da nu Gbogbo eni abi lo ma ku ẹh a ẹh Iwa ta a wu lo ma ku ẹh a ẹh Ọlanrewaju ọmọ oba E ma suure da gba o Won ni ko ṣe were roora ṣe E ma suure da gba oo Olooto ko ni ku sibi ọtẹ oo Ọlanrewaju ọmọ mi E ma suure da gba o Olooto ko ni ku sipo ika oo Olooto ko ni ku sibi ote oo Ọlanrewaju ọmọ ọba Ee ma suure dagba oo Ọlanrewaju ọmọ mi Ee ma suure da gba oo