Take Me High
Cristian Ferrer
4:40Osupa ti nran l'oke aja Aye njo bi ayo de Aje l'omo wa o je be Igba nlo awa ns'oro Erin sokale wa lo kiri Omi tutu l'ara mi re Igbalode aye yi to Wa je ka sere pelu Mofe wole diwo si mi Boti n'lu awo da po Wahala no fit catch mi Gbogbo aye njo lowo Ara mi ti gbo s'awa Awa lomo ale aye Ni ibere ati opin Nigbati alafia wa Ololufe e si w'aye Yodi si bi igbi'wo Ile aya ti dun'ra Ka jumo wa f'oye mi Mofe wole diwo si mi Boti n'lu awo da po Wahala no fit catch mi Gbogbo aye njo lowo Ololufe e si w'aye Yodi si bi igbi'wo Ile aya ti dun'ra Ka jumo wa f'oye mi Mofe wole diwo si mi Boti n'lu awo da po Wahala no fit catch mi Gbogbo aye njo lowo Ara mi ti gbo s'awa Awa lomo ale aye Ni ibere ati opin Nigbati alafia wa Ololufe e si w'aye Yodi si bi igbi'wo Ile aya ti dun'ra Ka jumo wa f'oye mi Ara mi ti gbo s'awa Awa lomo ale aye Ni ibere ati opin Nigbati alafia wa Ololufe e si w'aye Yodi si bi igbi'wo Ile aya ti dun'ra Ka jumo wa f'oye mi