E Ti Tobi To (Live) (Feat. Pelumi Deborah, Bbo & The Ohemgee Choir)
Emmaomg
13:47Ko su wa lati ma ko orin ti igbani Ogo ye Ogo f'Olorun Aleluya [A le fi igbagbo o] A le fi igbagbo korin na S'oke kikan Ogo f'Olorun Aleluya [Oya omo eh] Omo Olorun ni eto Lati ma bu s'ayo Pe ona yi nye wa si Okan wa ns'aferi Re [Okan wa ns'aferi Re] Nigb'o se a o de afin Oba wa Ologo Ogo f'Olorun Aleluya Now the new one You cannot know this one Should I sing it? Eyin te fe Oluwa [E fi ayo yin] E fi ayo yin han [E jumo ko orin didun] Eh E jumo ko Orin didun E jumo ko Orin didun [K'e si y'ite na ka] K'e si yi 'te na ka K'e si [K'e si eh] Yi 'te na ka Oya [A nyan a nyan ye] A nyan lo [Si Sion] Si Sion [Sioni o] Sion to l'ewa julo [A nyan goke] A nyan goke lo si Sion [Ilu Olorun] Ilu Olorun t'o l'ewa Wo'sss Let me go deeper Won tu ni pe Mo ti ni Jesu l'ore O j'ohun gbogbo fun mi eh Oun nikan l'Arewa Ti okan mi fe [ti okan mi fe] Oun n'itanna ipado Eh On l'enikan na [oh oh oh] T'O le we mi Kuro ninu ese mi [Olutunu mi l'O je sing] Olutunu Mi l'O je [raise it] N'nu gbogbo wahala [Oun ni ki n k'aniyan] Oun ni ki n k'aniyan Mi l'Oun lori [Oun ni Itanna Ipado] Oun ni Itanna Ipado [Ehhhhh] Irawo owuro Oun nikan L'Arewa Ti okan mi fe E e le m'eleyi lai lai Won ni pe B'o ti dun Lati gba Jesu Gbo gege Bi oro Re [K'a simi lo ri ife Re] K'a simi Lo ri 'leri Re [Sa gbagbo l'Oluwa wi] Sa gbagbo [ehh] L'Oluwa wi [Jesu Jesu Jesu] Say eh Jesu Jesu Emi gbagbo [Mo gbekele n'gbagbogbo] Mo gbekele n'gbagbogbo [Jesu Jesu o ehh] Jesu Jesu Alabukun [ehh] Ki nle gbekele O si [I want to go deeper, deeper] Wo'sss Wo ni Fi iyin fun Jesu Olurapada wa [Ki aye] Ki aye [k'okiki ife Re nla] K'okiki Ife Re nla [Fi iyin fun Eyin Angeli ologo] Fi iyin fun Eyin Angeli Ologo [F'ola at'ogo f'oruko Re] F'ola at'ogo Fun oruko Re [Olugbala t'O f'ara da irora nla] Olugbala t'O F'ara da Irora nla Ti a fi Ade egun De l'ori Jesu ye Ko tun si Wahala fun wa mo Eh eh eh eh eh Tori O l'agbara Lati gbala Oya e so wi pe A f'ope f'Olorun [L'okan ati l'ohun wa] L'okan ati l'ohun wa [Eni s'ohun iyanu] Eni s'ohun 'yanu [N'nu eni t'araye nyo] N'nu eni t'araye nyo [Gba t'a wa l'om'owo] Gba t'a wa l'om'owo [S'oun na l'o ntoju wa] On na l'o ntoju wa [O si nf'ebun ife] O si nf'ebun ife [Se 'toju wa] Se 'toju wa sibe E ma ni Ogo Ni f'Oluwa [to se ohun nla] To se ohun nla [Ife lo mu k'O fun wa ni Omo Re] Ife lo Mu k'O fun Wa ni Omo Re [Eni t'O f'emi Re] Eni t'O f'emi Re [lele f'ese wa] Lele F'ese wa [To si si'lekun iye sile fun wa] To si S'ilekun Iye sile fun wa [Oya yin Oluwa] Yin Oluwa [Eyin Oluwa] Eh! Yin Oluwa [Eyin Oluwa o] F'iyin fun Oluwa [Eyin Oluwa o] Yin Oluwa [Eyin Oluwa] Yin Oluwa [E yo niwaju Re] E yo niwaju Re [Ka to Baba wa lo] [l'Oruko Jesu] Ka to [Baba wa lo] Baba wa lo [l'Oruko Jesu] L'Oruko Jesu Je k'a jo F'ogo fun Onise-yanu Let's go deeper E so wi pe Eyin Oba Ogo On ni Olorun Yin fun 'se 'yanu ti O Ti fi han [O wa pel' awon ero] O wa pel' awon Ero mimo l'ona O si je imole won L'osan l'oru Eyin eyin eyin angeli didan [Everybody say] Eyin angeli didan [lu duru wura o] Lu duru wura [Ki gbogbo nyin juba o] Ki gbogbo nyin juba [t'e nwo oju Re] T'e nwo oju Re [Ni gbogbo 'joba Re ehhh] Ni gbogbo 'joba Re [b'aye ti nyi lo ooo] B'aye ti nyi lo [Ise Re y'o ma yin] Ise Re y'o ma yin [Ise Re y'o ma yin yeeeee] Ise Re y'o ma yin Fi ibukun Fun Oluwa Okan mi Eje k'a f'inu didun [Yin Oluwa Olore] Yin Oluwa Olore [Anu Re oo] Anu Re Yio wa titi [Lododo dajudaju] Lododo Daju Daju [On nipa agbara Re] say On nipa Agbara Re [F' imole s'aye titun] F' imole S'aye titun [Anu Re yio wa o] Anu Re Yio wa titi Lododo dajudaju Lododo Daju Daju B'a se n yin Oluwa logo Eni pe Ojo ibukun Y'o si ro [ileri ife] Ileri ife l'eyi [A o ni itura didun ye] A o ni itura didun [Lat' odo Olugbala o] Lat' odo Olugbala [Ojo ojo ibukun eh] Ojo ibukun [Ojo ibukun l'a fe o] Ojo ibukun l'a fe [Iri anu nse yi wa ka] Iri anu Nse yi wa ka Sugbon ojo l'antoro Tori wipe Tori Jesu ni Balogun oko Ema se je ka f'oya Olutoko wa ni Jesu Yio mu oko wa gun'le [E ma se beru ye] E ma se beru Ekun fun ayo Nitori Jesu L'oga oko [B'oti wu ki 'ji na le] B'oti wu ki 'ji na le to [Yio mu oko wa gun'le] Yio mu oko wa gun'le One more time E ma se beru beru ye E ma se beru [Ekun fun ayo o] Ekun fun ayo Nitori Jesu L'oga oko [B'oti wu ki 'ji na] B'oti wu ki 'ji na le to Yio mu oko wa gun'le Tori wi pe Asegun Ati ajogun Ni a je [Nipa eje Kristi a ni isegun] Nipa eje Kristi A ni isegun [B'Oluwa je tiwa a ki yo subu] B'Oluwa je tiwa A ki yo subu [Ko s'ohun to le bori agbara Re] Ko s'ohun to le bori Agbara Re Are you ready, are you ready? [Oya asegun ni wa o] Asegun ni wa [Asegun] Nipa eje Jesu [Baba yio] Baba fun Wa ni 'segun [nipa eje] Nipa eje Jesu [Eni t'apa f'elese] Eni t'apa F'elese [Sibe O wa O njoba] Sibe O wa O njoba [A ju asegun lo] Awa ju Asegun Lo Awa ju Asegun Lo Say Gbogbo Aye Gbe Jesu ga [Angel' e wole fun] Angel' E wole fun [Angeli o] Angel' [e wole fun] E wole fun [E mu ade] E mu Ade Oba Re wa [e se l'Oba] Se l'Oba A l'Oba A l'Oba A l'Oba A l'Oba A l'Oba A l'Oba Se l'Oba Awon Oba Eni Gbogbo aye Gbe Jesu ga Angeli E wole fun [eh eh eh eh] E mu ade Oba Re wa Se l'Oba Awon Oba [gbogbo aye o] Ye o Gbogbo aye Gbe Jesu ga Angeli E wole fun E mu ade Oba Re wa Se l'Oba Awon Oba E se l'Oba Eyin Martyr Ti npe ni Ni pepe Re [E ki Eni t'o gba yin la] E ki Eni T'o gba yin la Se l'Oba Awon oba Gbogbo aye o Gbogbo aye Gbe Jesu ga Angeli E wole fun E mu ade Oba Re wa Se l'Oba [Wo'sss] Awon Oba The easiest way Out of any kind of problem in your life Is for you to declare The kingship of Christ Is for you to declare Him as Lord See, the very very first Introduction we had to Christ in the Bible One of the first introductions Isaiah 9 verse 6 It says, for unto us a Child is born Unto us a son is given, and what? The government Will be upon His shoulders Telling you his Ruleship Then later in the Bible It says For God has exalted Him to the highest place And He has given Him a name That is above all else That at the name of Jesus Every knee shall bow And every tongue confess That what? Jesus Christ is Lord Whatever your issue is It can't be beyond Heaven And beyond earth And beyond under the earth And the Bible says Their knees will bow At the declaration Of the kingship of Christ Gbogbo aye Gbe Jesu ga Angeli E wole fun [E mu ade] E mu ade Oba Re wa Se l'Oba Awon Oba Tori tani yio gùn ori oke Oluwa lọ? Tabi tani yio duro ni ibi-mimọ' Rẹ'? Ẹniti o ni ọwọ mimọ' Ati aiya funfun Ẹniti kò gbé ọkàn rẹ' kale soke si asan Ti kò si bura ẹ'tan On ni yio ri ibukún gbà Ati ododo lọwọ Olorun igbala rẹ' Eyi ni iran awọn ti nṣe afẹri Rẹ' Ti nṣe afẹri Rẹ, Olorun Jakobu Ẹ gbé ori nyin soke, ẹnyin ẹnu-ọ'na Ki a si gbé nyin soke, ẹnyin ilẹkun aiyeraiye Ki Ọba ogo ki o wọ'le wa Tali Ọba ogo? Oluwa ti o le, ti o lagbara Oluwa ti o lagbara li ogun Ẹ gbé ori nyin soke Ẹnyin ẹnu-ọ'na Ki a si gbé yin soke Ẹnyin ilẹkun aiyeraiye Ki Ọba ogo ki o wọ'le wa Tali Ọba ogo? Oluwa Olorun awọn ọmọ-ogun On na li Ọba ogo [Eh e mu ade o] E mu ade Oba Re wa Se l'Oba Awon Oba [Gbogbo aye o ye o] Gbogbo aye Gbe Jesu ga Angeli E wole fun [E mu ade] E mu ade Oba Re wa Se l'Oba Awon Oba