Caricature
Fola
3:02Hm, wahala, wahala Ọja wọ pallor, pallor o (Another World) They give me just one minute before we conclude Bo ṣe mu ayọ mi kún, mi o le gbàgbé Ma mú ẹ lo Timbuktu, a ma kiss mọjú, ko ma mọ pe Ṣe you see as you dey jẹjẹly gbé s'aya, ìwọ ṣa ni messiah (hm-mm) And mo fẹ ka ṣe ni impromptu, when I'm done, wá ní mo sọ bẹ Go tell everybody (oh, sọ fun ẹnìkan) Ògiri o sa, mi o yọra, when you touch my body, oh Lord Ọmọ, I want something You're my healer, lọ ilé, how we be living lavida Steady giving me loving Ọmọ, ọmọ, original Torí your baka yi o, o wa vigilant Baby, you're my rhythm, I no fit lie To ba jẹ n de'bẹ, ma mọpẹ wa It's you that I crave for, t'ojo bá n rọ, ah Things I go do if everything go well, no be minor Hm, girl, I be your nigga, mo ni, "Ko si ìjà" A nígbàkúgbà, on a lock up O rí pe o ma n dùn bí vanilla She get all the thing I like o, ṣo le bọ'ṣọ? Oh-ah, wo ọmọ bo ṣe sanra Baby, tell me say, 'it's now or never' And upon all the trauma, ah Sun mọ mi, ka lo ṣere Denver Tell everybody (oh, sọ fun ẹnìkan) Ògiri o sa, mi o yọra, when you touch my body, oh Lord Ọmọ, I want something You're my healer, lọ ilé, how we be living lavida Steady giving me loving Ọmọ, ọmọ, original Torí your baka yi o, o wa vigilant Baby, you're my rhythm, I no fit lie To ba jẹ n de'bẹ, ma mọpẹ wa It's you that I crave for, t'ojo bá n rọ, ah Things I go do if everything go well, no be minor They give me just one minute before we conclude Bo ṣe mu ayọ mi kún, mi o le gbàgbé Ma mú ẹ lo Timbuktu, a ma kiss mọjú, ko ma mọ pe Ṣe you see as you dey jẹjẹly gbé s'aya, ìwọ ṣa ni messiah And mo fẹ ka ṣe ni impromptu, when I'm done, wá ní mo sọ bẹ