Anyam Abu O
Jaymikee
4:15E ba mi ki Olurapada E ba mi ki Olurapada Nitori to shey oun pupo fun omo araye Nitori anu re duro lailai E bami ki Olurapada E bami ki Olurapada Apata ayeraye mo ki o o baba mi Alagbara giga, giga, giga Alagbara to n gba mi lowo ajunilo Kii ba ti la gbara re Ko se un ti la gbara re Olugbala, Oludande Olurapada, Olugbeja Oluranlowo, Ata aiye se Atorise Mo ti fi Jesu shey abo, Oun ni ibi isadi mi Lowo, lowo iranlowo Baba ti dide iranlowo fun mi A ti gbemiga ori apata ayeraye, a ko ni shi mi ni po rara A ti ramipada, a ti so mi do omo Mo jade ninu idalebi Ah, ah, ah, ah, mo gba idalare Ninu Jesu Oluwa E ba mi ki Olurapada E ba mi ki Olurapada Nitori to shey oun pupo fun omo araye Nitori anu re duro lailai E bami ki Olurapada E bami ki Olurapada Ara ba ri biti, Ari bi rabata Gba ni gba ni ti aye n saya Gba ni gba ni ti Orun n bo Olori Ogun, Asaju ogun Akeyin Ogun, Akikanju loju ogun Iwo la gba ni lowo ija Baba mi arogun da ade, Arogun ma ti di Olugbeja mi oh, oh, oh Gba ni gba ni, Mu ni mu ni Yo ni yo ni, La ni la ni Olusegun, Aja segun O gbe ni ni'ja ke ru ó bo nija lojo ija Baba mi onikan gbe ra re nija o Ta ni iwo oke niwaju Zerubabeli Lojiji odi dandan ki e di ite mole Mo gboju mi soke nibi iranlowo mi yio a ti wa Iranlowo mi n be ninu oruko Oluwa, ah, ah, ah, ah A ti gbe mi nija Mo ti ju asegun lo E ba mi ki Olurapada E ba mi ki Olurapada Nitori to shey oun pupo fun omo araye Nitori anu re duro lailai E ba mi ki Olurapada E ba mi ki Olurapada E ba mi ki Olurapada Nitori to shey oun pupo fun omo araye Nitori anu re duro lailai E ba mi ki Olurapada E ba mi ki Olurapada