Ope Ye Jesu
Tope Alabi
6:29Lv: Ore ope l’emi muwa, Ore re o po jaburata, Ko de se simi, gege bi ti iwa mi, Aanu ni mo ri gba lowo olorun mi Chrs: Ore ope l’awa muwa, Ore re o po jaburata, Ko se siwa, gege bi ti iwa wa, Aanu la ri gba lowo olorun wa Lv: Opo l’ore ta o foju ri Ko s’eni, t’olu o fi’re fun, Chrs Af’eni to b ani tire oto Aanu la ri gba lowo olorun wa Lv: Opo l’ore ta o foju ri Resp: T’a o foju ri, Ah, ah Lv: Ko s’eni, t’olu o fi’re fun, Af’eni to b ani tire oto Aanu la ri gba lowo olorun wa Chrs: A e o, Ijinle ife t’oni siwa Lafi nyan, fanda fanda 2ce Chrs: Ose eleru niyin a m’ope wa wa A dupe onile ayo, tewo gb’ope wa Ose eleru niyin a m’ope wa wa A dupe onile ayo, tewo gb’ope wa Elenkule adewure, oni’sun ayo wa T’ewo gbope ti a muwa T’ewo gbope ti a mu wa (till fade)