Oro Towo Baseti

Oro Towo Baseti

King Sunny Ade

Длительность: 3:38
Год: 2003
Скачать MP3

Текст песни

Ohun gbogbo t'Oluwa yo se fun wa
maa je owo gbeyin rara tori
oro towo ba seti ile lo n gbe
ewa wo n towo se, nile aye tawa yi
owo lo n se nkan ire
owo lo n se nkan gidi
Edumare funmi ni temi o
kin rowo fi jaye

Ohun gbogbo t'Oluwa yo se fun wa
maa je owo gbeyin rara tori
oro towo ba seti ile lo n gbe
ewa wo n towo se, nile aye tawa yi
owo lo n se nkan ire
owo lo n se nkan gidi
Edumare funmi ni temi o
kin rowo fi jaye

bi eniyan ba mbe laye
bi o ba lowo rara
adabi r'eni to ti ku
ti won o ti gbe si koto
laye mi se
Adura wa ni pe

Ohun gbogbo t'Oluwa yo se fun wa
maa je owo gbeyin rara tori
oro towo ba seti ile lo n gbe
ewa wo n towo se, nile aye tawa yi
owo lo n se nkan ire
owo lo n se nkan gidi
Edumare funmi ni temi o
kin rowo fi jaye