Adara
Labisi
3:50Atabatubu Olodumare Oba mimo Oba mi olola Oba mi ologo Oba imole Kabiyesi Olodumare Eni to d'aye at'orun To dami laworan re Abiyamo ode orun Atabatubu Olodumare Oba pipe Oba to momi, Oba to moomi Omi imi e simi Sebi iwo lo ni kin maa mi Lo ni kin maa yo Lo ni kin maa yonfanda o Ninu ogo gangan lo tin fohun Ninu ola nlanla lo tin sise Ah n o yin o logo N o se o loba N o sa ferire re Oba mi olola Oba mi olola Ti Baba lase o, ti Baba loye Ti Baba lase o, ti Baba loye Ni ghohungbohun oro re Emi mimo bale mi Ara mi si ya gaga Ti Baba lase I lean on Oro ti n gbenu omo eda sise On your word Eyi ti n gbenu omo eda d'ogo On your word oh God Olodumare, Oba akoda, Oba aseda On your word oh God T'o ba ti n s'oro be naa ni o Ti Baba lase o, ti Baba loye (I lean on) Ti Baba lase o, ti Baba loye (On your word) Ni gbohungbohun oro re (On your word oh God) Emi mimo bale mi Ara mi si ya gaga (On your word oh God) Ti Baba lase Oremi atata Baba Alailenikan Eni to femi o K'aye to momi