Osan (Orange)
Oriyomi Kehinde
14:10Oshi oda mamase fi kanmi oluwa Iya oda maje kiya o jemi laye Adaniwaye iwo ni oba to ngbola Feniyan to rope kole da laye Oshi oda mamase fi kanmi oluwa Iya oda maje kiya o jemi laye Adaniwaye iwo ni oba to ngbola Feniyan to rope kole da laye Maa sha Allah Emi gbolohun gbo nigba toba ri bakan Mogba f'Allahu mi nigba to nruju Tori b'Olohun ba sola oun lemi a yin Eni kanju sare aye, oun lo npasan Gbigba f'Olohun mi agba oore ni Oshi oda mamase fi kanmi oluwa Iya oda maje kiya o jemi laye Adaniwaye iwo ni oba to ngbola Feniyan to rope kole da laye Bee Oba tomomi momi, mio bawon kanju Adua nikan ni momo tole gbemi debe Se temi nirorun, gbogboun ton nsare fun Fowo si figbakun kun, f'oro kun kope Je konma gbo oruko mi lawujo olola Gbemilo sibi toga, oke gogoro Oshi oda mamase fi kanmi oluwa Iya oda maje kiya o jemi laye Adaniwaye iwo ni oba to ngbola Feniyan to rope kole da laye Allah Mase f'adanwo kan awon oloore mi Iwo loyan won timi, tnbo ma gbola F'awon toje wipe b'owo se nwole were Won ma pemi febun, fi oun toda toda ranse Bami sebukun funwon, konle ma lola si Bami dabo re bowon konle ma gbaye Oshi oda mamase fi kanmi oluwa Iya oda maje kiya o jemi laye Adaniwaye iwo ni oba to ngbola Feniyan to rope kole da laye MashaAllah Alhaji bravo yekini olayiwola Moni e laye mi, moti gba ibukun mo koore Alhaji yekini bravo ayinde olaniyan Iwulo re lawujo ko kere rara Orin kope kope lanko, afe kope Kale jola e pe bose njola oluwa Olayiwola esin re osi o, ibaje re osi o Olayiwola egan re osi lowo babanla enikan Bareni tose fun ti iruwon oba moore Tiwa ni o wo, mawo t'awon tio moore Sungbon olowo nsore olowo, olola nsore arawon Awon afenifere, won ma gbafa funrawon Hajji yekini yi lawon tie Awon tonjo joloriire Awon ton jonse oun todatoda, lawujo olola aye Olayiwola hajji yekini, eyan omogbolahan adigun saidi mi Oba mobil afenifere ni Bo ri adigun o rowo o rola, o soriire Eyan alhaji kabiru yaro Ibiyemi kabiru yaro Seri yaro ju bee losewa lo Oun o pariwo ola e lon npariwo Awon leyan layiwola hajji yekini mi To funmi lashiri kan, mo njola adura yen lo Ah aah ah ah! Lailaha illa anta, subhanaka inni kuntu, mina dzolimeen Lailaha illa anta, subhanaka inni kuntu, mina dzolimeen Ko soba toye ni singing afiwo Allah, iwo logaju ni ola Boòseda aye kole siun tinjaye, boòseda orun kole si Kosenikan afiwo loba Lailaha illa anta, subhanaka inni kuntu, mina dzolimeen Baba mi hajji yekini akanmu oloro, oko mariamo ola Awon adua e kole gbe lailai Ibaadah re kole ja sasan, awon malaika tigbo Won ti gbadua e goke lo Lailaha illa anta, subhanaka inni kuntu, mina dzolimeen Bami ke ju bose nkemilo Ba ngbega ju bose fega lo Tii leyin ju bose ntimi leyin, alhaja bola amoke ade o maria Bami ke ju bose nkemilo Ba ngbega ju bose fega lo Tii leyin ju bose ntimi leyin, alhaja bola amoke ade o maria Maa sha Allah Omobolanle mariamo mi amoke alase mummy blue kitchen Lame houston texas Asejere ni kowonu ise e lo Alhaja mariam amokeade oniparun Gbola fun ju bose nkemi lo Bami ke ju bose nkemilo Ba ngbega ju bose fega lo amin Tii leyin ju bose ntimi leyin, alhaja bola amoke ade o maria Oriyomi mopade oloore, modi mowon lateyin Won f'oja ponmi akanni kinmale jabo rara Atokotaya won, won gbami sinu ebi won Omobolanle amoke ade o mariam, iwo sha maso oun toba tunku fun Olohun Oore kiito, oore tun ku leyin tomarigba Alhaja bola, majola Olohun milo Bami ke ju bose nkemilo Ba ngbega ju bose fega lo Tii leyin ju bose ntimi leyin, alhaja bola amoke ade o maria Amoke aya prince kolawole kazeem mi Abass alesinloye, molayo pe moba e se Estate developer ni houston l'america ati nigeria Omo olubadan akoko oluyole gangan Alesinloye abass to j'olubadan akoko Akolawole prince oko amoke Baba adbulsalam ayinde oniyanku funwa Baba engineer abdulkareem mi akanji Baba ridwan akanmu toje army lamerica Gbogbo ebi e, won o mani dawati laye amin Bami ke ju bose nkemilo Ba ngbega ju bose fega lo Tii leyin ju bose ntimi leyin, alhaja bola amoke ade o maria Ewo! Oju oloore, eele gungi lowo mi Temi nie wo, temi nie wo ema wo teni tio moore Aloju oloore, eele gungi lowo mi Temi nie wo, temi nie wo ema wo teni tio moore Alhaji lateef olumegbon tobi lowomi Akanni okin lati olanrewaju mi Kofi wonmi wo, o kan ngbe kiki funmi ni Olumegbon ajaye lati olanrewaju mi Oko alhaja sumaiyah, big hajjia legbo yen Oko queen of queens haliyah lanrewaju mi O dami mo omo to o, bukata mi oma suwon Oju oloore, kole gungi lowo mi Temi nie wo, temi nie wo ema wo teni tio moore Hajji nurudini adisa ademola mi Omo adedunmoye do good rereloluwa C.e.o ademola oba estate Afinju developer to tunje valuer Oko khadijah adisa oko nasiroh Onse temi otunse tawon to sunmo mi Oju oloore, eele gungi lowo mi Temi nie wo, temi nie wo ema wo teni tio moore Hajji zakariyah ayinde olamide mi Eni Olohun da tiko mase farewe ni Oko habiba ajiun lolamide mi Oko molayo ajoke todara leeyan Baba sanusi layinka, baba omogbolahan Baba adulrahman alabi omo bolanta Baba kolawole abdulrohimi Baba amina ashabi lolamide mi Oju oloore, eele gungi lowo mi Temi nie wo, temi nie wo ema wo teni tio moore Hajji rashidi amole, ebudola mi Jejelayegba omotoso baba alaye mi Alase jeje haulage hajji rashidi Ile tuntun tunti kun tile base ntoro Soranti moso ninu ojo ayo pe ile tuntun Eyi toba mako leyin re matun gara Mo debe mofoh mokan sara, peleyi tun le gan Ki gbogbo ola e mase baje o, koma parun Eyan alhaji brahimo ishola, popoola mi Oju oloore, eele gungi lowo mi Temi nie wo, temi nie wo ema wo teni tio moore Iwo loma jere iwa re toba serere Iwo loma jere iwa re toba serere Aniwo loma jere iwa re toba serere Iwo loma jere iwa re toba serere Iwo loma kesan iwa e toba sebi Iwo loma kesan iwa e toba sebi Maa sha Allah Iwo nsare pe kobaje feda egbe e ni Nise lotunwa nyalatako feni fe seun re Kaka kotun ba onire yo inu nbi e ni Won o pe e sibi ode ri kooje won gan Odajo ode pe kero lewa konba e se Ooreyan wa soju e tija soresan ibi Iwo loma kesan iwa e toba sebi Sewo toje gbogbo igba e lofi nse rere Binse nkanre toba timo, oma dasi ni Koda kojegba to lowo, oma nara ni Towo bawa owo to koto, oma funwon kun Won o ba e nidi ibaje, nibi koda ni Wero bose po nigba to kan e, sowa tiri o? Pewo loma jere iwa re toba serere Iwo loma jere iwa re toba serere Aniwo loma gbesan iwa re toba serere Iwo loma jere iwa re toba serere Maa sha Allah Maa sha Allah