Igbadun
Oriyomi Kehinde
6:11Akankatan, oore olohun lemi ntoro Ajenjetan, ola olohun lemi nfe K'atigoke, ayemi mase dona inira Akankatan, oore olohun lemi ntoro Ajenjetan, ola olohun lemi nfe K'atigoke, ayemi mase dona inira Gbese lewu, toma ndabi akisa o Mi kiise ayamasan, ola Olohun lemi nreti Ahun nonpemi, koyewon pe mo mofun Awon muwa muwa Mo funwon mofi sedupe Lasikoyi Mowa nbelohun ilahi Komaje nmo mo B'ikoro senri lara temi mo Akankatan, oore olohun lemi ntoro Ajenjetan, ola olohun lemi nfe K'atigoke, ayemi mase dona inira Setiri oko oro Tonma nso sawon akobi Tiko tete la, won o nife fun laponle Bonpe ipade, ajoro ninu molebi Won ani kotete de, oro owo dele kori da Aitete ni, tonfa k'egbon daburo Atoshi atishe, olohun bawa le pelase Kolo tefe-tefe, koma wogbo lo nfemo Allah lana irorun, kire wole kona o shi Ara towumiiiiiiii Ara towumi, koje nle raye ati ma da Akankatan, oore olohun lemi ntoro Ajenjetan, ola olohun lemi nfe K'atigoke, ayemi mase dona inira Allahuma iniy, iniiiy Allahuma iniy, ahudzu bika mon zawal Watahawwul, watahawul afiyatik Wa fajihati, wafajiati niqmatik Wajaami-i, wajami-i sakhatik Olohun alanaaa ooo, Olohun alana Tonitola titi ainipekun Iwo lolupese, gbogbo nkan tomo eda nfe Gbagbara womi, jekin ma rona ati ga lo Akankatan, oore olohun lemi ntoro Ajenjetan, ola olohun lemi nfe K'atigoke, ayemi mase dona inira Ore maase sodaqo K'olohun leseke fun e kun Maase saaraa, k'olohun le lae nibi ewu Eni tio ni lo ntoro je Kororun keda o bosi igboro Edakun egbami ntori Olohun Òpò won nio tun ni rigba Kaka k'awon kan o funwon lowo Bi ewure nonma lewon, modupe t'olohun semi ni funni funni Oremi osi ma tore Iwo naa se sodaqo K'olohun leseke fun e kun Maase saaraa, k'olohun le lae nibi ewu Ntajo nreti lori ona oore Adeun tonse funwa Tati sokale pe taba rigba Wipe ao rale kama kole lo Aniyan tipo taa dale Mu inu enikan dun kojo tope Konise koniye oma rire gba o Olohun aseke atore Oje yaase sodaqo K'olohun leseke fun e kun Maase saaraa, k'olohun le lae nibi ewu Ore maase sodaqo K'olohun leseke fun e kun Maase saaraa, k'olohun le lae nibi ewu