Ope
Oriyomi Kehinde
26:29Interlude MashaaAllah, k'alafia makuro larami Arun tonje ki gbajumo o dole Magbe bawa karigba wa lope Tunbo sowa dasiko agbantara K'alafia makuro larami Arun tonje ki gbajumo o dole Magbe bawa karigba wa lope Tunbo sowa dasiko agbantara Won lemi loju, sungbon alafia loba Aimoye eniyan tonlola ton lowo Sungbon arun nio je kongbadun owo naa Lojojumo lowuro tonbaji Oogun oyinbo tonkomi lojumo O po ju ounje telomi a je tayo Oba alase tonpase to ribe F'alafia fi ropo arun won K'alafia makuro larami Arun tonje ki gbajumo o dole Magbe bawa karigba wa lope Tunbo sowa dasiko agbantara MashaaAllah K'aisan madi oun todarun tonpani B'aisan bape londarun tongbe ka Aitete mo leje karun kan lasan Onje ko darun ti won osima nawo Bi eni toferan koje nkan todun Toba wanje nkan sugar lojumo Ti jedijedi bawa di ito sugar Yio pada feyi sarun ton ntoju Arun tonse gbajumo ton dole, magbe bawa karigba wa lope o Masowa dasiko agbantara K'alafia makuro larami Arun tonje ki gbajumo o dole Magbe bawa karigba wa lope Tunbo sowa dasiko agbantara Ijamba oko tonsele tojepe, abarapa wa deyan to nlogi Lojo kejo march 2022, nisele tosele simi lona ilorin Emi at'adisa emir omo mi Lati eko si ibadan d'ogbomoso a koja Ona òté nilorin lade lona bayi, motor ba yari mo ismaila mi lowo Bimose woke, igbo ma la unri, ninu koto laba arawa logan, emi tiro pe iku loma jasi Awa jonse la ilaha illa Allah Ao kan lowo, kan lorun, kan lese Oko lo sonu emi o bo adupe Alafia lopada wa joba K'alafia makuro larami Arun tonje ki gbajumo o dole Magbe bawa karigba wa lope Tunbo sowa dasiko agbantara Naam Olohun loba Afinimona Maje ka sonu, kato le sonu Olohun loba Afinimona Maje ka sonu, kato le sonu Yah robbi, Olohun loba Adaniwaye, Olohun loba Afinimona Maje ka sonu, kato le sonu Olohun loba Afinimona Maje ka sonu, kato le sonu Ba'da Bismillahi, iniy tawakalitu ala llahi robiy warabikum Maa min daabatin illa huwa Akhizun bina siyaatiaa, inna robiy ala siratin mustaqeem Olohun loba Afinimona Maje ka sonu, kato le sonu Ha, oba tonsike, oba tonsike, oun lolupese tola e oletan Tonseje atimu fun gbogbo eda, maje a je gbese, katole rina Olohun loba Afinimona Maje ka sonu, kato le sonu Yah robbi, adua mi kowole ase, mo fore orun pelu oore aye Mafikan dikan Koma fikan gbakan Mase ikan yokan Koma yokan atikan Toba tun sekan Kinmawa ni ojukan Ki ikan majo ikan Koromi makan Olohun loba Afinimona Maje ka sonu, kato le sonu Allahumma robbana, taqobal mina, innaka anta semiul aleem Moseba foba, oba to nigba, mo bowo agba, awon to nlogba Nigba taidagba Mogba f'onigba, kadua migba Oore to ju ígbá, oore tose gbangba ni kemi ma rigba Olohun loba Afinimona Maje ka sonu, kato le sonu Eni nwa nkan timoni lodo, ka pade arawa Bee leni toni oun timo nwa, ka pade arawa Kiwa ni temi timoni lodo, orin lebun mi Tolowo, tolola ton moyi orin, ati oluranlowo Pelu awon fans mi, ton fife bami lo, kapade arawa Taba pawo lode anlo si studio, ka gborin otun yo Kinu aye ledun komasi depression, kale pa ironu re Lawon olola aye fin funwa lebun, pekafi se iwuri Bonse nfunwa lowo na nfunwa ni motor, pekafi sewuri Won bunwa nile funwa ni materials, pekafi sewuri Won fin dunwa ninu base nmu inu won dun, pekafi sewuri T'onise owo tosu, toni karakata, pekafi sewuri Eni nwa nkan timoni lodo, ka pade arawa Bee leni toni oun timo nwa, ka pade arawa Wa gbemi pade alaanu obare, ígbá tobaya t'asiko bato Maje ka dota arawa, maje ka koyin sirawa Wa gbemi pade alaanuuu, uun, obare Wa gbemi pade alaanu obare Ìgbá tobaya t'asiko bato, maje ka dota arawa, maje ka koyin sirawa Kinma koyin si alanu obare, maje ndota alaanu toran wa Kinma pada wa jorami loju, koma gbemi pade alanu lojumo Igbá tobaya t'asiko bato, maje ka dota arawa, maje ka koyin sirawa Konma fi ishan arami demi Allah, kota mayomi pebo lofe gba Magbemi jeri elenini laye, koran alagidi ninu awon ota lewon Koma gbemi pade alaranse asoore Igbá tobaya t'asiko bato, maje ka dota arawa, maje ka koyin sirawa MashaAllah Ojojumo lonyato, lojojumo lonpo Owo mi lodo agunwa, lojojumo lonposi Ojojumo lonyato, lojojumo lonpo Owo mi lodo agunwa, lojojumo lonposi Sing phrasing bigger fan (Alhaji abdul rasheed akanmu agunwa) Ile mi lodo agunwa, lojojumo lonfesi Ojojumo lonyato, lojojumo lonpo Owo mi lodo agunwa, lojojumo lonposi Sing phrasing bigger fan (Alhaji abdul rasheed akanmu agunwa) continues, ipomi lodo agunwa Lojojumo longasi Ojojumo lonyato, lojojumo lonpo Owo mi lodo agunwa, lojojumo lonposi Sing phrasing bigger fan (Alhaji abdul rasheed akanmu agunwa) ashiri agunwa, lojojumo lonbosi Ojojumo lonyato, lojojumo lonpo Owo mi lodo agunwa, lojojumo lonposi Adeleke ado lola otun niwa kun, eniyan nie hajji abdullahi ado Olohun ma mata loshi, ayinde babatunde Adeleke ado lola otun niwa kun, eniyan nie hajji abdullahi ado Olohun ma mata loshi, ayinde babatunde Mentioning the names of one of my big fan (Alhaji abdullahi adeleke olufunsho ado) okuleyin lowi abdullahi ni ko tan K'olohun mama ta loshi, ayinde babatunde Adeleke ado lola otun niwa kun, eniyan nie hajji abdullahi ado Olohun ma mata loshi, ayinde babatunde Mentioning the names of one of my big fan (Alhaji abdullahi adeleke olufunsho ado) ikomora loni tero finpo leyin e Konibaje f'adeleke ayinde ado Adeleke ado lola otun niwa kun Eniyan nie hajji abdullahi ado, Olohun ma mata loshi, ayinde babatunde Owo afunni oke longbe Beeni oke ni Bee, gbogbo funnifunni oke nonwa o, beeni oke ni MashaAllah Owo rashidi amole nko, beeni oke ni Lokeloke f'omotosho mi amole jeje Beeni oke ni Mentioning the name of my big fan (Alhaji abdul rasheed jeje amole) eebudola omotosho loke Beeni oke ni Mentioning the name of my big fan (Alhaji abdul rasheed jeje amole) amole jeje eebudola Tori owo afunni oke lonwa o Beeni, oke ni Toriwipe bose nseni komani roju toba ti nnawo, awa gan damo, awa gan damo atiri Kole kabamo Kole kabamo, po nnawo Awa gan damo, awa gan damo, atiri Kole kabamo, kole kabamo, po nnanwo Atiri Kole kabamo, kole kabamo po nnawo Atiri Kole kabamo, kole kabamo po nnawo Atiri Kole kabamo, kole kabamo po nnawo Interlude Mo lenikan mogba potida Nise nile ayemi wa ndun Ajala luku zangallo Abejide angeli mini Mo lenikan mogba potida Nise nile ayemi wa ndun Ajala luku zangallo Abejide angeli mini Narrating and mentioning (Alhaji lukman zangallo's) support on my career Abejide malaika mini Mo lenikan mogba potida Nise nile ayemi wa ndun Ajala luku zangallo Abejide angeli mini Haa, s'ajala nwo tenikan momi nio Mio mo, mio mo, koyemi Abi nitoripe lucky mi loje o Mio mo, mio mo, koyemi Abi onwo ti tolufimo osupa parapo Mio mo, mio mo, koyemi Abi ti lajero oladimeji o, abi ti engineer innocent, abi ti ak money hajji hakeem Abi tejire oyinbo onirin ni Boya eyin gan rope lucky mi loje o Mio mo, mio mo, koyemi Sungbon: Kole tan l'Olohun miwi Kole tan lolohun miwi Koletan, nise nio tunma po Awa naa, koni dake adura Kola yen tunma po o T reign on da mix, ina oni tanwo won Gbogbo eni to nponwa le Gbogbo eni tonyewa si Gbogbo eni ton nponwa le Olohun lose yakubu lasiwaju Olohun lose nah God lasiwaju Ogboriefon yakubu tiose ro seyin Iwo ko Olohun loti ko bee, seri towo nina, yakubu o kere o Olohun lose yakubu lasiwaju, Allah lose yakubu lasiwaju Ogboriefon yakubu tiose ro seyin Iwo ko, Olohun loti ko bee, seri towo nina, yakubu o kere o Allah tun fun koniwa kan random Yah robbi lofun koniwa kan random Alabosi ole ba yakubu sore o, baba eniola onigba pe kon yan eni kankan je Afarun iwaju pomo tipako jawo, kenikan yannije Ogbori efon oma nigba o Olohun lose yakubu lasiwaju, Allah lose yakubu lasiwaju Ogboriefon yakubu tiose ro seyin Iwo ko, Olohun loti ko bee, seri towo nina, yakubu o kere o MashaAllah Nah God o gbeyin ba dode owo nina Yakubu oni saun lola e se nlekin, aimoye eniyan ton o nisun lale moju Ogboriefon nonse adua fun mojumo Koletan, ola toni oni ditan Gbogbo ojo laye, koma rilo koma rina Allah lose yakubu lasiwaju, Allah lose yakubu lasiwaju Ogboriefon yakubu tiose ro seyin Iwo ko, Olohun loti ko bee, seri towo nina, yakubu o kere o Bee, omaku itoju mi, ogboriefon oseun Ashiri e (nah God) konitu loju aye Ooni bawon dasa, adanwo ko sowo mo Oko morufa, oko baraka bolaji Baba malik, baba ilyas Banki tobi dollar, alase fathia Fathia motors lori elebu express Eyan oluyole alhaji moruf Ton nkoni re makkah fun hajji ati umura Modupe esegan te nkemi po bi oba Monbe e Olohun, magba alafia ara Ogboriefon alhaji yakubu Komase ri ajoba, pelu awon ore e, Haa itesiwaju ninu owo ati ola Allah lose yakubu lasiwaju Ogboriefon yakubu tiose ro seyin Iwo ko, Olohun loti ko bee, seri towo nina, yakubu o kere o Molenikan komo bonse nsako, i.b.d o mo bonse nsote o Koniregun kotun ni motomoto Komo bonse nsako, i.b.d o mo bonse nsote o Koniregun kotun ni motomoto Greeting alhaji Ibraheem dende (omo egungbohun) koma mo bonse nsote o Konidaru koniburu f'ajao dende Komo bonse nsako, i.b.d o mo bonse nsote o Komo bonse nsako, i.b.d o mo bonse nsote o Koniregun kotun ni motomoto Greeting alhaji Ibraheem dende (omo egungbohun) bosense mani ola e fi nlekun Konibaje koni buru f'ajao Komo bonse nsako, i.b.d o mo bonse nsote o Koniregun kotun ni motomoto Naam I.b.d tisise sile koto majere o, egungboun tisise sile koto dola o Won ni kema wule wo ago alaago sare Ani ke ma wule wo ago alaago sare Ore mi joo sonu koma sonu, torile aye tawayi, paddy mi kole, kole, kole, ko gbagidi Kole, kole, kole, ko gbagidi Mentioning Alhaji ibraheem dende's relatives I.b.d tisise sile koto majere o, egungboun tisise sile koto dola o Won ni kema wule wo ago alaago sare Ani ke ma wule wo ago alaago sare Ore mi joo sonu koma sonu, torile aye tawayi, paddy mi kole, kole, kole, ko gbagidi Mentioning Alhaji ibraheem dende's relatives Won ni dende tisise sile koto majere o, egungboun tisise sile koto dola o Won ni kema wule wo ago alaago sare Ani ke ma wule wo ago alaago sare Ore mi joo sonu koma sonu, torile aye tawayi, paddy mi kole, kole, kole, ko gbagidi Kole, kole, kole, kogbagidi Al-aliyah hajj & umura, ile ise tose fokan tan nitiwa Oba tongba fun ile isewa Koni ko funwa o Kajo ririn ajo, fun hajji ati umura Al-aliyah hajj & umura Oba tongba fun ile isewa Koni ko funwa o Kajo ririn ajo, fun hajji ati umura Al-aliyah hajj & umura Oba tongba fun ile isewa Koni ko funwa o Kajo ririn ajo, fun hajji ati umura Alarafa mi, koni sasedanu amin Gbogbo alarafa mi, koni sasedanu amin Gbogbo alarafa mi, koni sasedanu amin Iposinsin wa, koni sasedanu amin Irokirika, koni sasedanu amin Ibaadah wa koni sasedanu amin Aah alarafami koni sasedanu amin