Meta
Oriyomi Kehinde
4:40Olohun bawa f'idunnu lebanuje lo Allah Idera to nyo, inira funni laye o Itura tonle, arun wo igbo lo lafe o Lawa fi ntoro idera pe kose o, ba wa tete se ao lelomiran juwo lo B'awa f'idunnu lebanuje lo Allah Idera to nyo, inira funni laye o Itura tonle, arun wo igbo lo lafe o Lawa fi ntoro idera pe kose o, ba wa tete se ao lelomiran juwo lo Yah robbi bawa f'idunnu lebanuje lo Allaaah Bawa f'dunnu lebanuje lo Allah Idera to nyo, inira funni laye o Itura tonle, arun wo igbo lo lafe o Lawa se ntoro idera pe kose o, ba wa tete se ao lelomiran juwo lo B'awa is f'idunnu lebanuje lo Allah Idera to nyo, inira funni laye o Itura tonle, arun wo igbo lo lafe o Lawa fi ntoro idera pe kose o, ba wa tete se ao lelomiran juwo lo Ha, iyawo enikan lo bimo loba fi bi ibeta o Oko iyawo gbo o, pe iyawo bimo tuntun Seri boko segbo lova fijo be erebe Sungbon nigba togbo pe meta lomo ko jomo Oko o de hospital toko fi salo O nibo lowo wa, toun o fi gbomo kosi o Oun ayo lomo tuntun sungbon kini yio se o? Kowu ko salo koma sowo ni Allah Gbogbo awon towa ninu condition pe sowo Dakun bawon fowo le oshi danu Tori wonti ntoro idera pe kose o Bawon tete se won e lelomiran, ju'wo lo B'awa is f'idunnu lebanuje lo Allah Idera to nyo, inira funni laye o Itura tonle, arun wo igbo lo lafe o Lawa fi ntoro idera pe kose o, ba wa tete se ao lelomiran juwo lo Awon agan won nfara ro nkan ko kere o Igba tonsese fe se lebi ko mora won re o L'odun kan ikeji tofi podun merin ko bimo Ati iya ati baba oko ton feran e rio Ati iya ti baba oko tonti so po nice Won lo kan njaje sanra ni ko f'orun bimo Won wa sofun iyawo pe taba pada wa ka b'omo Afairi omo lilo loo lo o Niya oko ati baba oko ba pada de won leju B'iyawo se kunle toku ko kiwon o O se bi eni tofe bì sare wo yara lo, awon ro poti loyun ni, niwon ba ndunnu o Èrù won lonba o lose dogbon bi po loyun Iyawo naa o ma mo, p'oyun tiwa lara o Leyin osu mesan o d'olomo laye o E w'ore iyanu nigba tio lero o Gbogbo awon agan ton nireti fun omo Allahu wahidu tete bawon se o Wa s'ore iyanu won o lelomiran juwo lo B'awa is f'idunnu lebanuje lo Allah Idera to nyo, inira funni laye o Itura tonle, arun wo igbo lo lafe o Lawa fi ntoro idera pe kose o, ba wa tete se ao lelomiran juwo lo MashaaAllah Ase at'abara to to'le aye gbe o, igbesi aye irorun ati alafia o Ati iranlowo ti ko latako ninu o Aanu tio se dede ojo ori ni mo toro Masaise funmi sebiwo lolase re lowo Idera tonle, oshi wogbo lo nmofe o Bami tete se mio lelomiran juwo nikan B'awa is f'idunnu lebanuje lo Allah Idera to nyo, inira funni laye o Itura tonle, arun wo igbo lo lafe o Lawa fi ntoro idera pe kose o, ba wa tete se ao lelomiran juwo lo Gbogbo ota tiwon tin nfiwa se yeye o Tiwon ma ndarin ayo lori ibanuje eniyan Ilekun ton ti se ton tiro poti o, Olohun bawa si kosi sile fun ire ayo Awon aye okunkun to njewa niya o Bawa tan imole, ko dayo funwa la toro Awa tun nbere aanu pekose Bawa tetese ao lelomiran juwo allah B'awa is f'idunnu lebanuje lo Allah Idera to nyo, inira funni laye o Itura tonle, arun wo igbo lo lafe o Lawa fi ntoro idera pe kose o, ba wa tete se ao lelomiran juwo lo Kini mofe kini iwo naa nfe o Ideraaa Kini mofe kini iwo naa nfe o Ideraaa T'olohun ba s'owo kama fi wo arun Ideraa T'olohun ba sola, koma d'ibaje o Ideraa Gbogbo dukia kama gbeta nio Ideraa Awon omo tabi kiwon ma yanku Ideraa Kise ma dise kama r'oja ta o Ideraa Kama se ribanuje lojo nkan eye wa, ideraa Kini mofe kini iwo naa nfe kowi na