Ogo
Oriyomi Kehinde
7:46Mori iyanu ni makkah ati madina, iroyin olohun koja ntaleso tan Mofe k'olohun je kinle malo, l'ododun fun hajji ati umura Mori iyanu ni makkah ati madina, iroyin olohun koja ntaleso tan Mofe k'olohun je kinle malo, l'ododun fun hajji ati umura MashaaAllah! Seri iyanu t'olohun se o kere ooo Iyanu t'olohun se o kere O jomiloju ninu irin ajo mi, ase esuntere ma wa npada d'ibu Ase oda pe k'ori ola jiya ri o Ori to lu igi ori to lu opè naa T'ori naa o bafo iya ori oun oni gbe Alhaji ejire t'awon aye ti pemi ri o, l'ero wipe won fin nbomi lashiri Bon npe alhaji timo bafi erin dahun Ma f'okan sope k'olohun o tetese ooo Mo sope k'olohun otete se ooo Mo nsope k'olohun o tetese 2019 l'olohun base iyanu Mo pada lo saudi eemeji lodun, iyanu ni Mori iyanu ni makkah ati madina, iroyin olohun koja ntaleso tan Mofe k'olohun je kinle malo, l'ododun fun hajji ati umura Béè Opo eyan tinrelu makkah tipe Won ma nroyin b'ise hajji seri o, oorun obe ole dabi anfi okele gbemi Iroyin o dabi afojuba ayafi T'eda bale m'oju e debe lo pe Mo raworase s'olohun o gb'ebe mi Umura ma l'olohun fi s'akoko o, l'odun kan naa Loba ti fikun ore odomi, iyanu ni mo pada tun sise hajji mi pe Iwo ma lose l'oore afikun Aniyan mi timo da latile o ju tesin lo Dakun ma ma sope o gba todomi, banse pe Moti iyanu ni makkah ati madina, iroyin olohun koja ntaleso tan Mofe k'olohun je kinle malo, l'ododun fun hajji ati umura Muhammadu f'oju ara e winaaa Muhammadu f'oju ara e w'ina Tori k'esin Olohun ma le pare Otun jiya tori emi ati iwo ni, ase ojiya tori ko bale dan o Kole d'osho tori emi atie ni Lada t'awon saabe nfi emi ro, t'ota nseku pawon o lona oro oo Won f'ana jiya tori oni awa ni Oun lo d'oni ti awa nfi irorun ri o More madina mori saare annabi Mo salamo s'asiwaju esin mi Eyombo annabi tinutinu e sope Sola llahu alayhi wa-sallam Oo! Muhammadu ola omo amina, baba fatimo, koba bami s'ike ati ige fun olawale Moti iyanu ni makkah ati madina, iroyin olohun koja ntaleso tan Mofe k'olohun je kinle malo, l'ododun fun hajji ati umura Olohun mo berue o to loba o to s'agbekele Iwo salemi oma sin titi lailai Iwo salemi o masin tinma ma wari fun Mo gba fun e o to loba o to s'agbekele Iwo salemi oma sin titi lailai Iwo salemi o masin tinma ma wari fun Jalla jalaaluhu oba tao fojuri To npase tao gbodo lao tele Oba asooo Oba aso to f'annabi s'asiwaju More makkah moriyanu tio lafiwe Ise olohun tao le fiwe t'eyan kan Irokirika kahabah kin s'akawe e O dabi registration pe mowa pe leain mani Ati submission k'oba gbami ni musulumi Mo f'ojumi kan kahaba toje ile nla Mori p'olohuuuuuun Mori p'olohun oba mi o ni afiwe Mogba fuuuun, mashaAllah Mo gba fun olohun ko seku s'aye kan o Ha, oun salemi o masin titi lailai Mo egba fun e o to loba o to s'agbekele Iwo salemi oma sin titi lailai Iwo salemi o masin tinma ma wari fun Mo sa safah, marwah mose umura Meje ni lilo meje pada ni abo ni Mowa seranti awon obirin ton loyun sinu Mo sadua fun gbogbo bimobimo aye Asokale anfani ni k'olohun se Oungbe ayo koma gbeyin lalai s'omi Eyi teo mu k'oba se l'omi idera Bi ti zam-zam, omi zem-zem Tose fun hajara lojosi, nigba tofi bi ismaila o se idera Atomi ara ati eje komase d'inira Mo gba fun olohun tio lafiwe o Iwo salemi o ma sin titi lailai Iwo salemi o masin, tinma ma wari fun Mo egba fun e o to loba o to s'agbekele Iwo salemi oma sin titi lailai Iwo salemi o masin tinma ma wari fun Mo gba fun e o to loba o to s'agbekele Iwo salemi oma sin titi lailai Iwo salemi o masin tinma ma wari fun Seri l'ojo kejo zul hijjah naa lojo Ti a bere fun ise hajji kodi asepe A roso mimo (Ihram) fun irin ajo wa A gba munah lo, a gba munah lo nibi ti gbogbo ibusun Tonpe ni bed oniha kan fun eniyan kan Taba jarunpa ao f'ara kan eniyan ni, boje olola ko sope koyato sira Adua kan ba wasi okan aya mi Toko tiyawo tiwon nsun sinu yara kanso tosije wipe kogbawon ooo Bon nsun lale orun bi t'elewon mani Pese funwon ko kole alara funwon oo Ti yio maje kiwon ma yin e titi lailai Iwo shani won o ma yin ton o ma dupe fun Mo gba fun e o to loba o to s'agbekele Iwo salemi oma sin titi lailai Iwo salemi o masin tinma ma wari fun A lo s'arafa lojo keji ni aye kan, ni arafa nibi tise hajji ti jepe Eni toba ti gbiyanju duro ni aye naa Lose hajji, eyan ti kodebe koni di alhaji, o pan dandan kade aye yen Awa l'arafa mo ranti ojo agbende, ni ojo ti olohun a bere ise Ti a gbaye se ni owo onikaluku Se igbiyanju atesin mi sowa le lami Yah robbi Oba mi toje oludajo Mase alaigba igbiyanju pelu esin mi Wola okan kan at'aniyan timowa fise Masomi sina tesin mi pelu igbagbo oo Fimi s'alijanna re kinle rope da Kiyen o ma j'esi ayo pe mo r'aye wa Mo gba fun e o to loba o to s'agbekele Iwo salemi oma sin titi lailai Iwo salemi o masin tinma ma wari fun Nigba ta kuro, muzdalifa lakori si, ni aye kan tao sun sile gberefu Elomiran leri aye sabe bridge Tasi gbodo sun ni aye ibi ti anwi, otutu, nibe lao wa di mojumo Mofi aye yen mofi toro fun awon eyan kan, toje ibikibi tile basu toba kawon mo Ibe nan o sun b'ojo banro nibe mani Se ibugbe, yowon kuro ninu iśe Ma tawon loshi je kon pada gbadun aye oo Toriwo shani won o masin ton o ma dupe fun Iwo shani won o masin, ton o ma gbola fun Mo egba fun e o to loba o to s'agbekele Iwo salemi oma sin titi lailai Iwo salemi o masin tinma ma wari fun Mio gbagbe aye kan, jamrah loruko aye naa Nibi tao lo lati lo soko fun shaiton Oko meje laso sojukan lojo akoko Lojo keji, mejemeje lona meta Ni ojo keta oko meje tun ni lona meta Base nsoko ni moranti awon eniyan Boku dede o kon rore gba ni ona kan Awon alatako, wonse idina funwon Gbogbo awon toribe fun Allahu mi Bawa soko fun Bawa soko fun, awon alatako to ndina mo won o Ha, konle ma rerin ayo konma ropeda Mo egba fun e o to loba o to s'agbekele Iwo salemi oma sin titi lailai Iwo salemi o masin tinma ma wari fun Oore ofe nimogba ogbon mi ko, igbiyanju mi nikan ko Olohun ni, seberawon tose jumi tio funwon Ol'asiko ti olohun nseke koowa Oore ofe nimogba ogbon mi ko, igbiyanju mi nikan ko Olohun ni, seberawon tose jumi tio funwon Ol'asiko ti olohun nseke koowa Alore ofe nimogba ogbon mi ko oo Oore ofe nimogba ogbon mi ko Igbiyanju mi nikan ko, olohun ni, seberawon tose jumi tio funwon Ol'asiko ti olohun nseke koowa Oore ofe nimogba ogbon mi ko, igbiyanju mi nikan ko Olohun ni, seberawon tose jumi tio funwon Ol'asiko ti olohun nseke koowa Oriyomi edakun ejo ema shimi gbo o Kiise po poju mio so wipe kotope Sungbon koi toba le se lalekun Kodin ola olohun ku tori kiitan Oore to bunmi olohun mi, ma kuro yah robbi kotun ma lekun Oore ofe nimogba ogbon mi ko, igbiyanju mi nikan ko Olohun ni, seberawon tose jumi tio funwon Ol'asiko ti olohun nseke koowa Seri b'olohun oba seto koye enikankan oo Ani b'olohun oba seto koye enikankan A bu ikan kun ase ikan kun yio po juralo Awon kan t'olohun o ni tete fun o Awon kan tun wa ton ma lo tio nipe to Shomi allahu mase je ki temi o tan o, wola iya timo jeri ninu aye Wola iya timo jeri, ninu ise Saanu mi mase je kitemi o gbe Oore ofe nimogba ogbon mi ko, igbiyanju mi nikan ko Olohun ni, seberawon tose jumi tio funwon Ol'asiko ti olohun nseke koowa Eniyan t'olohun ba yan toje alaanu eni, tojepe kotun wa wuwa bi p'osu rara Afi ki aki onitoun p'oku omoniyan Oba bamiso rashidi akanmu agunwa Mentioning the supports & supports of alhaji abdul rasheed agunwa bakare (C.e.o glory land estate) Eyi onije asegbeyin aje opo oore Eniyan t'olohun ba yan toje alaanu eni, tojepe kotun wa wuwa bi p'osu rara Afi ki aki onitoun p'oku omoniyan Oba bamiso rashidi akanmu agunwa Appreciating the supports & supports of alhaji abdul rasheed agunwa bakare (C.e.o glory land estate) Oko alhaja balikisu mi mi alarafa nko? Oko oluwatoyin rashidi agunwa Eniyan t'olohun ba yan toje alaanu eni, tojepe kotun wa wuwa bi p'osu rara Afi ki aki onitoun p'oku omoniyan Oba bamiso rashidi akanmu agunwa Appreciating the supports & supports of alhaji abdul rasheed agunwa bakare (C.e.o glory land estate) Oba bami salekun ike fun agunwa Eniyan t'olohun ba yan toje alaanu eni, tojepe kotun wa wuwa bi p'osu rara Afi ki aki onitoun p'oku omoniyan Oba bamiso rashidi akanmu agunwa Oba tose anu awa lofun wa ni Aisha kama le toshi laye ti awa Alhaja yetunde ashabi gbenusi mani, k'olohun bawa da emi e si kajola e pe Oba tose anu awa lofun wa ni Aisha kama le toshi laye ti awa Alhaja yetunde ashabi gbenusi mani, k'olohun bawa da emi e si kajola e pe Appreciating the supports & supports of alhaja aishat ashabi yetunde sanyaolu (Alias gbenusi) Oriire tio letan tia tun ran omo o, niki gbenusi ma f'ayo se igbesi aye e loni amin Oba tose anu awa lofun wa ni Aisha kama le toshi laye ti awa Alhaja yetunde ashabi gbenusi mani, k'olohun bawa da emi e si kajola e pe Appreciating the supports & supports of alhaja aishat ashabi yetunde sanyaolu (Alias gbenusi) Sebi eni olohun bafi timi oye kinse, aponle fun kole mope oju bee lo ni Oba tose anu awa lofun wa ni Aisha kama le toshi laye ti awa, hajja yetunde ashabi gbenusi mani K'olohun bawa da emi e si kajola e pe Oya kare ile jennifer madina, ajoke madina Mama alabi bryan Mama olumide waliyullahi mama rofia S'ajoke tio k'ore olohun bintin, jennifer o ma mu t'olohun tashere Bose ndupe lori emi e o bosewa Bee lon fola aye e fi sore Ajoke tio k'ore olohun bintin, jennifer o ma mu t'olohun tashere Bose ndupe lori emi e o bosewa Bee lon fola aye e fi sore Appreciating alhaja Medinah ajoke jennifer's supports towards Koni juwo si ola e pe bye bye Yah hayyu, yah qoyyumu koma nilo ni amin Ajoke tio k'ore olohun bintin, jennifer o ma mu t'olohun tashere Bose ndupe lori emi e o bosewa Bee lon fola aye e fi sore Appreciating alhaja Medinah ajoke jennifer's supports Toko tiyawo kole alara o koja pe, k'eyan o sope oun o ri daada Zaaaaanga! Olufokantan toje alanu, zangaaallo Zangallo Appreciating and praising alhaji lookman ajala abejide zangallo Zangaaaallo Tonile talejo ewa, ara ile ero ona Ebaje kajo ki, eniyan pataki kan, ton fola e setemi o Onilenla, ba sa yasin bi egberun fun qomarudini Idzawaka bi egbefa fun O ju beelo Tonile talejo ewa, ara ile ero ona Ebaje kajo ki, eniyan pataki kan, ton fola e setemi o Onilenla, ba sa yasin bi egberun fun qomarudini Idzawaka bi egbefa fun O ju beelo Naam Qomarudini onilenla ayinde, alafe mi abiodun O feran mi gege bi oju o Osetemi bi ishan ara, ayinde feran mi dokan debipe o Gbogbo eniyan toba setemi o L'alalafe tunma da lola, mio ma riru onilenla ri setiri Pe bi aka yasin bi egberun fun qomarudini Idzawaka bi egbefa fun, oju beelo Tonile talejo ewa, ara ile ero ona Ebaje kajo ki, eniyan pataki kan, ton fola e setemi o Onilenla, ba sa yasin bi egberun fun qomarudini Idzawaka bi egbefa fun O ju beelo Appreciating alhaji qomardeen onilenla (Abbey de don) in germany continues Tonile talejo ewa, ara ile ero ona Ebaje kajo ki, eniyan pataki kan, ton fola e setemi o Onilenla, ba sa yasin bi egberun fun qomarudini Idzawaka bi egbefa fun O ju beelo Appreciating alhaji qomardeen onilenla (Abbey de don) in germany continues Tonile talejo ewa, ara ile ero ona Ebaje kajo ki, eniyan pataki kan, ton fola e setemi o Onilenla, ba sa yasin bi egberun fun qomarudini Idzawaka bi egbefa fun O ju beelo Konkobilo da o, odaa Hajji latifu daa, odaa Tori p'olohun lodaa da, odaa Sori Gbogboun tofi da, odaa Koni shalai da, odaa Toripe ajeye da gan, odaa Appreciating alhaji abdul lateef konkobilo Oh Loje k'adigun latifu d'eni aye nfe, adigun ajeye d'eni aye nponle Iwo shama sope mashaallah Alhaji lati ajeyee, adigun ajeyee Kokonbilo oju anu re o le fo Moma ri onitemi ejire, layemi ba darinrin Owo b'owomu ejire, l'ogo ayemi ba d'ayeye T'ajosepo ba yo eso, olohun lofe kajose T'owo tola ba gba ibe yo, olohun lo fore kun Babatunde saidi adisa, seboun lose bebe Ase o pemi o ejire, kinwa soriire ni O gbabe o dalase role model L'olohun ba f'oresi (Entertainment) Mo l'olohun lofi bere o, l'olohun ba foresi Torimi lose bere o, l'olohun ba foresi Appreciating alhaji babatunde saheed (mr sport) c.e.o role model entertainment Konibaje fun awon ton o fe kobaje funwa, nitoripe bi aye awa yiose dara Lojewon logun k'olohun shama salekun ola nla Appreciating fans from all places around the globe Nitoripe bi aye awa yiose dara Lojewon logun k'olohun shama salekun ola nla Appreciating fans from all places around the globe Nitoripe bi aye awa yiose dara Lojewon logun k'olohun shama salekun ola nla Appreciating fans from all places around the globe Nitoripe bi aye awa yiose dara Lojewon logun k'olohun shama salekun ola nla Appreciating fans from all places around the globe Nitoripe bi aye awa yiose dara Lojewon logun k'olohun shama salekun ola nla Alhaja ganiya odee, l'america o Ni chicago ni yankee sha longbe Aramide ganiya aya olaide Baba so e ni ganiya o t'oloruko o yangan Iya so e l'odee o o soriire nio, aramide oti de e lade Appreciating alhaja ganiyat aramide & alhaji wasiu alaka and children Seri p'oruko nro omo o e, onro omo Onlapa laye omo o a, onlapaa Oruko rere san ju wura o daju fadaka lo Appreciating fans from all places around the globe Seri p'oruko nro omo o e, onro omo Onlapa laye omo o a, onlapaa Oruko rere san ju wura o daju fadaka lo Appreciating fans from all places around the globe Seri p'oruko nro omo o e, onro omo Onlapa laye omo o a, onlapaa Oruko rere san ju wura o daju fadaka lo Appreciating fans from all places around the globe Seri p'oruko nro omo o e, onro omo Onlapa laye omo o a, onlapaa Oruko rere san ju wura o daju fadaka lo