Ife Owo
Oriyomi Kehinde
30:18Jerryson production Tanadi arawa, koma ma da erora Oun abase loni, bo dola a yiwa Tanadi arawa, koma ma da erora Oun abase loni, bo dola a yiwa Naam Oun tomaje ti teni, kole fonida laye Teda ba nsebaje sibi tati ndogbon Pe kebi ma pomo wa atiyawo wa ni Benikan fe dina atije atatimu wa K'olohun bawa febi atedi se tiwon Kota o toro je kosi ni moribo Tanadi arawa, koma ma da erora Oun abase loni, bo dola a yiwa Nemesis loyinbo ma npesan toba de Eni tonse rere loni kole gbe laye Koda bonfibi su, yio gbesan toba ya Eni aba seka fun, kokan miri lasan Esan a ke dandan, nigba toba ke tan Sereni to nsebi fun nlati jeka toba ya Tanadi arawa, koma ma da erora Oun abase loni, bo dola a yiwa Sababi arawa, eyi taba fe je Kaje si ti rere laiseka funrawa Oun abase loni, bo dola a yiwa Malaika tonko rere, otun londuro si Eyi to nko tibi, egbe keji londuro Sapamo kajori, ama wo e rekete O koja pe moti ti ilekun mi ni kokoro Tanadi arawa, koma ma da erora Oun abase loni, bo dola a yiwa Ore o gbe e iro lopa, o lowokan ika ninu Bareni tonse rere, ko ma legbe laye O le ma jodo eni, to fokansi rarara Ma foju sunbi ore, p'oma gbawa to ba ya Yoruba ntenumo, oro kan won a wipe Basore fun arara, omiran la gbewa Tanadi arawa Koma ma da erora Oun abase loni, bo dola a yiwa Wa semi lakin, fidunnu tami lore Maje nbekun sun, maje nbekun ji Wa semi lakin, fidunnu tami lore Maje nbekun sun, maje nbekun ji Oba mafaye mi sile, kemi nikan o dagbe Loni alo jeun, enikan lo mowo le Ola alo raso, enikan raso funmi Bonse nsore funmi, jekinle ma se funyan Konma yomi legbe, wa tete tami lore Ma je nte lebi, ma yomi lara Wa semi lakin, fidunnu tami lore Maje nbekun sun, maje nbekun ji MashaAllah Nigba ti ko sowo, moma wa lalafia Towo bawa de, ma faisan demi mole Maje kin foshi mo awon eyan tiwon femi Kaye ma fiku mo iwa timoni toda Kin se party rero, kin bale mo entokomije Kin nfowo pelere, ko f'apo shaka k'owo lo Wa semi lakin, fidunnu tami lore Maje nbekun sun, maje nbekun ji Eni to sun lale ana pelu sadness O ji loko keji, koma masi happiness Gba p'olohun loba tole sore express Lo fokan bale. Ko lewa ni readiness Pa ironu ti. Kole wa ni wellness Tori tola bade, koba e pelu fitness Wa semi lakin, fidunnu tami lore Maje nbekun sun, maje nbekun ji Bee! Oore ofe lari gba o, oore ofe lari gba o Awa naa ko, isesi wa naa ko lodaju, oore ofe lari gba o Oore ofe lari gba o, oore ofe lari gba o Awa naa ko, isesi wa naa ko lodaju, oore ofe lari gba o Yaaa robbi Olohun oma ku ise o, ni gbogbo igba monrise e Nidi isemi mohan nbe o, aga niwaju lo tomi sio Emi naa ko, isesi mi naa ko lodaju Oore ofe nmori gba o Oore ofe lari gba o, oore ofe lari gba o Awa naa ko, isesi wa naa ko lodaju, oore ofe lari gba o Allah Okiki ayo nile wa, ariwo ayo nilemi Aanu e timoma tinwa o, koje nrigba loni o Womise laanu, adua mi oba je o gba, oloore ofe ni o, Allah Oore ofe lari gba o, oore ofe lari gba o Awa naa ko, isesi wa naa ko lodaju, oore ofe lari gba o MashaAllah Oba atobiju ma funmi lo, o kuku timo ma dupe o Oore totun-tosi jenri gba o, oore tiwa teyin ko bami Maje ko fomi, koma kojaa mi yah robbi Oloore ofe ni o ooo Oore ofe lari gba o, oore ofe lari gba o Awa naa ko, isesi wa naa ko lodaju, oore ofe lari gba o Morire gba mo kore, ire ayomi nlekun Emi rire gba mokore, ire ayomi nlekun Moni kin femi ro ni, loba gbabe ja sope Inumidun mojelo, modupe koja s'asan Ma beru maselo, aimoye danwo tonjawo Opportunity ojo kan ma nsoni deyan laye Morire gba mokore, ire ayomi nlekun Emi rire gba mokore, ire ayomi nlekun