Teramo (Feat. Imodola Mr Wisdom, Omo Oriyomi & Zainab Abeke)
Oriyomi Kehinde
14:51MashaAllah Aole ma serawa Iyen o ma je tuntun Sungbon ka jaja diju Iru e lonfa ègún Eje ka f'oni satunse, tori ola awon omo Aole ma serawa Iyen o ma je tuntun Sungbon ka jaja diju Iru e lonfa ègún Eje ka f'oni satunse, tori ola awon omo Akanni mo l'alaye, feni bawu ko tetigbo o Oro debi shàán làárìn, kama wule pé koro Aole mo owo arawa, koma dija lojokan Lojo toro ba dija, ko séèwò ka binu Taba reyan da soro E je kagba p'otilo It's gone (Otilo) Aole ma serawa Iyen o ma je tuntun Sungbon ka jaja diju Iru e lonfa ègún Eje ka f'oni satunse, tori ola awon omo Setiri Won fe iyawo lerawon Iyen o ma je tuntun Tiyawo tiyale nja Ewo ni ti iya sófó To gbenu ofofo wa Iyale nba iyawo e ja Iyen normal koni meaning Ka parie funwon ni Iyen o tun ni konma ja Sebi tegbon taburo Ton biwon telerawon Sebi awon naa ma nj Kama so'ja d'ogun ni Aole ma serawa Iyen o ma je tuntun Sungbon ka jaja diju Iru e lonfa ègún Eje ka f'oni satunse, tori ola awon omo Tomo tiya teba nja, kema je kija o d'ogun Omo obàkan loba nja Ema je koran bi ina E yema so loju omo Ni akoko teba nbinu Awon omode teriyen Won ka oro kun ju awa gan lo Won a ni daddy loso: ka jina si egbon won Won a ni mummy loso, kama lole aunty won T'awon obi bawa lo tan, won a wa d'ota ara won Eje ka f'oni satunse, tori ola awon omo ni Aole ma serawa Iyen o ma je tuntun Sungbon ka jaja diju Iru e lonfa ègún Eje ka f'oni satunse, tori ola awon omo Ija oni tio tan boro, loma npada di ote o, o ooh! O ooh! Ina ote tio ba ku, loma npada di ogun Ogun oni to pari ti, egun tirantiran ni Isokan ni e jeawa Kaye ma ri ija bi nkan Tao sope koni tan mo Alaroka nikan leyan Timo le jina si pata Mio ni koma soriire Mio leni ko shanku Taba rira ka kirawa, understanding lafiyen se Aole ma serawa Iyen o ma je tuntun Sungbon ka jaja diju Iru e lonfa ègún Eje ka f'oni satunse, tori ola awon omo Jerryson production Olohun, maje kaye f'ikoro Sinu adun toose Karaye ma fabo mi, poko ibanuje Toreni afe lamo, ao m'eni feni denu Maje kaye f'ikoro Sinu adun toose Karaye ma fabo mi, poko ibanuje Toreni afe lamo, ao m'eni feni denu Anrin ao weyin, ao meni nsoni laye o Igba tao gbin eèbù ìkà, Allah nio s'oluso wa Aori tenikan ro, baose rise lawa nle Eni nri ilosiwaju wa bi competition Igba tio fimo wipe awa o ri tenikan ro Ojo ati dale nbi toti nsogba onigba Maje kaye f'ikoro Sinu adun toose Karaye ma fabo mi, poko ibanuje Toreni afe lamo, ao m'eni feni denu MashaAllah Awon omo labi kale, tanro bon ose deyan nla Lojo ririje lojo airi, anse eto wa Nigba toba t'asiko, tafe majere omo Olohun ma pana emi, ka gbaye jere omo Karaso da karaso lo, katun rile fiwo Asiko t'ounje ba rele, koma koro lailai Maje kaye f'ikoro Sinu adun toose Karaye ma fabo mi, poko ibanuje Toreni afe lamo, ao m'eni feni denu Olopa loma nf'odaran Tofi ngbokun lenu ise Bi soldier sende loju ogun Ton ngboye repete Ika nfaye enire, fi gbokun odaju Kiwon le ma gbinberu Sokan awon enire Maje kiwon tamilofa, ààbò e lemi nfe Ati iso e timomo po nipon j'ewu irinlo Maje kaye f'ikoro Sinu adun toose Karaye ma fabo mi, poko ibanuje Toreni afe lamo, ao m'eni feni denu Oba Olohun mi ma ma loje kin tegbe O kamiye moma pada daun timofe da Ibanuje ti wabigba o somi dalayo Titi aye lope F'olohun to lope Oba Olohun mi ma ma loje kin tegbe O kamiye moma pada daun timofe da Ibanuje ti wabigba o somi dalayo Titi aye lope F'olohun to lope Mo ranti ojo totipe o Moripe opeyemi Lojojumo lope Titi ayeraye Eni bamo boseri funmi Ntipe! Tipe!! Tipe!!! A mope ojo tipe Tatin nfàsán denu Kotodi powa dope, tio sebimo to dayo Kosibi mo odire o, orin ope ma loyemi Titi aye lope F'olohun to lope Oba Olohun mi ma ma loje kin tegbe O kamiye moma pada daun timofe da Ibanuje ti wabigba o somi dalayo Titi aye lope F'olohun to lope Bee Ojo kan nbowa, timo mo poma de Koni bami ni saree Ma dajo ope ma tun Te invitation pe kewa Kajo darin ope Mo nbelohun ko shola Feni towu lati wa Tori powumi kowa Yess iwo, mo lowumi kowa Joko si high table mi Titi aye lope o, fun Olohun to lope Oba Olohun mi ma ma loje kin tegbe O kamiye moma pada daun timofe da Ibanuje ti wabigba o somi dalayo Titi aye lope F'olohun to lope Ore, momo kinikan tipe o Ironu o da nkan Asiko tofi nronu Ko sadua lomaye Toripe eni nsunkun O nko letter sarun ni Ba sunkun oore made Bao sunkun oore made Konida koju tifo, koto dipe oore made Konida kapa tiro Nitori e maronu o Iwo shama dupe F'olohun to lope (Oya) Oba Olohun mi ma ma loje kin tegbe O kamiye moma pada daun timofe da Ibanuje ti wabigba o somi dalayo Titi aye lope F'olohun to lope (E pemi) l'awo akoko o Mo sope ko (Bamise) (Agbega) moni mofe o Sewari potise (Mo l'olohun) to ngbope (Idera) malo funmi Loje ki (Opeyemi) O pada tunwa se (Oore) Motun wa belohun pe o (Ogbon) timo fefise Komaje ko wonmi Kinle r'ayo mi lope o Titi aye lope o F'olohun to lope Oba Olohun mi ma ma loje kin tegbe O kamiye moma pada daun timofe da Ibanuje ti wabigba o somi dalayo Titi aye lope F'olohun to lope Interlude Tolahal badiru alaena (alaena) Min tseniyatil wadahi (wadahi) Wajabal shukiru alaena (alaena) Man daha lilahi (daahi) Ayo wa jeko soju orewa (ore wa) Ire wa koma seyin ota wa (ota wa) Kalejo wobi tan o foju si (fojusi) Awon tan o gbero kale debi a fede (ti afe de) Kon pada woran bonse kesan iwa won (awon iwa won) I hoped to be the winner of the battle (mo dasegun) I later overcome all of my sorrow (mo dasegun) Mo gbero lati segun opo ogun (i am a winner) Mo mati bori gbogbo isoro (I am a winner) Tolahal badiru alaena (alaena) Min tseniyatil wadahi (wadahi) Wajabal shukiru alaena (alaena) Man daha lilahi (daahi) Yah robbi mafi akisa gbeyin aso wa Mafi egungun keyin eran wa Mafi ibanuje keyin ayo funwa o Mafi gangangan gbeyin opolo Mafi akisa keyin aso wa Mafi egungun keyin eran wa Mafi ibanuje keyin ayo funwa o Mafi gangangan keyin opolo Kawon alaini pada wa lola Làálâ kòókō won o nija s'asan Won jiya pupo gan, je konpada wani Tonba pada wa nitan, ma maje kotan Ma dagba pada saida kon tesiwaju Mafi ibanuje gbeyin ayo funwon o, mafi gangangan gbeyin opolo Mafi akisa keyin aso wa Mafi egungun keyin eran wa Mafi ibanuje keyin ayo funwa o Mafi gangangan keyin opolo Kawon olola wa mapada toroje Konma pada wa bewa fun owo yiya Kawon dukia mama se parun Anjola won kon tesiwaju Ma mase fisoro gbeyin ola funwon o, mase fekisa gbeyin aso amin Mafi akisa keyin aso wa Mafi egungun keyin eran wa Mafi ibanuje keyin ayo funwa o Mafi gangangan keyin opolo Naam, aduro t'olohun mi malo raye gbe Koni jogun ofo kole se lasan Taba nsadua ka fokan si pore ade Tori adua longba kii s'agbara Mapada leyin mi jowo oba rere Koma f'aburu keyin awon ore wa Mafi ibanuje keyin ayo funwa o Mafi gangangan keyin opolo Mafi akisa keyin aso wa Mafi egungun keyin eran wa Mafi ibanuje keyin ayo funwa o Mafi gangangan keyin opolo Oba tonsomi o leku (oba ni) Taraye banku oun o leku (oba ni) Tomo eda bante oun o le te (oba ni) Tomo eda banku oun o leku (oba ni) Oba tonsomi o le te (oba ni) Oba ni (MashaAllah) (oba ni)