Gbese
Qdot
4:03Òní wàràpá tí rọlú mágún (kasa!) Ko kan mi, ko kan mi Qdot lórúkọ mí (ko kan mi, ko kan mi) Mo mọ pe ẹ mọ mí lẹ ṣé ń f'ọbọ lọ mi Mí o l'órí, lo gùn pé ibọn ó lé rán mí Bíbélì mo ní pẹlú Qurani Pẹlú kí ní báà mí tó ń dùn woro-woro Ẹní f'ojú dí iná, iná à jo Ìyá Ìbàdàn, ó yà, gb'àgbo lè'ná Èpò ọgẹdẹ kò lé yọ mí Máa pẹ bí Aláàfin Ọyọ ní Wèrè ní wọn, mó má lé wọn s'Aro Má gbé wọn lọ bí t'òdò Ìyá Aláró Ẹ fún mí l'hammer, kí n fọ wọn lórí ká Àwọn wèrè, àwọn motherfucker Ẹ ro dáadáa kẹ to b'Èṣù lówé Ẹ sọ fún Ṣígidi, kò má r'odò lọ wẹ Kí ló ń jẹ' kò s'ewé, kò s'egbò nínú àyé? K'Ọlọrun májẹ à rí'já àyé ní Ṣi-ọ, kẹlẹbẹ (ko kan mi) Wọn ní pé picker die (ko kan mi) Pé client ó sọrọ mọ (ko kan mi) Pé ìyàwó yín ṣé oloṣo (ko kan mi) Ó n sún yàrá landlord (ko kan mi) Wọn fẹ mọ idí abájọ (ko kan mi) Ta ní Bàbá Alájọ? (Ko kan mi) Ẹ re ilé bàbálawo (ko kan mi) Ẹbọ yìn má fọ m'awo (ko kan mi) Wọn ni pé Yahoo ní (ko kan mi) Wọn ni pé à ṣ'ogun owó (ko kan mi) Òní wàràpá rọlú mágùn (ko kan mi) Pé lagbaja b'ójú kọ'rin (ko kan mi) Ẹní òyìnbó ó dùn lẹnu mí (ko kan mi) But local mí ń ja'wó (ko kan mi) Òkè Kilimanjaro sọ pé Ọlumọ ó gá À gbọ' t'ajá, à gbọ' t'ẹran Èwo ní t'àgùntàn lórí àga Wọn ní mọ local, mo ń pa'wó lọ Ọmọ Folashade, mo tí gba'dé lọ Òyìnbó lé má dùn lẹnu mí Èyí tí ń bá sọ, Wole Soyinka l'aba yìn tu Ẹ wá wo ẹlẹkọ tó yàn'dì s'oní moi-moi Òní bùgan bínú ẹlẹ́wà àgóyìn I don't care if you like or not Ẹní ṣíṣẹ ló má pa'wó Kòkòrò tó ń jó leba ọna ní, onílù rẹ ń bẹ nínú igbó Mó tí gòkè, mó tí ṣé lọ k'afara tó já Mó japa, k'òyìnbó tó já Ọmọdé àná tí wá d'àgbà Qdot, ọmọ imalẹ afeleja Ẹ ro dáadáa kẹ to b'Èṣù lówé Ẹ sọ fún Ṣígidi, kò má r'odò lọ wẹ Kí ló ń jẹ' kò s'ewé, kò s'egbò nínú àyé? K'Ọlọrun májẹ à rí'já àyé ní Ṣi-ọ, kẹlẹbẹ (ko kan mi) Wọn ní pé picker die (ko kan mi) Pé client ó sọrọ mọ (ko kan mi) Pé ìyàwó yín ṣé oloṣo (ko kan mi) Ó n sún yàrá landlord (ko kan mi) Wọn fẹ mọ idí abájọ (ko kan mi) Ta ní Bàbá Alájọ? (Ko kan mi) Ẹ re ilé bàbálawo (ko kan mi) Ẹbọ yìn má fọ m'awo (ko kan mi) Wọn ni pé Yahoo ní (ko kan mi) Wọn ni pé à ṣ'ogun owó (ko kan mi) Òní wàràpá rọlú mágùn (ko kan mi) Pé lagbaja b'ójú kọ'rin (ko kan mi) Ẹní òyìnbó ó dùn lẹnu mí (ko kan mi) But local mí ń ja'wó (ko kan mi) Jirafa jalika ra fali eli Malaika mí Orimọlade Ẹní f'ojú dí iná, iná à jo Ìyá Ìbàdàn, ó yà, gb'àgbo lè'ná Èpò ọgẹdẹ kò lé yọ mí Máa pẹ bí Aláàfin Oyo ní K Sir Sosse King of Marley Musa Felix for Garuba Femi Jaguar nílùú London Mo mọ Baddy Oosha Lanre Typical Milli ọmọ Salawe Mo mọ Femi Chill Music Mo mọ Billique (mo mọ Billi') Mo mọ Doctor Brown Mo mọ Arowolo, Arowolo tí ń tá motor Mo mọ Bottles, IBD Dende Aláṣẹ Nikas Teni Level Mo tí mọ Water Mo mọ Owo Mabo Bunmi simple casher Mo mọ Unique Motors Mo mọ Climax Mo mọ Pasuma Wonder, ọmọ ìyàwó Anọbi l'Omole Xsmile (Yeah, who's here?) Quick as sure boys