365 Days
Tml Vibez
2:57Mbolo, mbolo Maami oh, maami oh Ubāmi me, kamala tō-oh, ma-ma pariwo (uhn-uhn) Old school vibe, handicap one, uhn-uhn Since I dropped Goated, ọmọ ọba, mo ti pa wọn, mm (I'm goated) Emi ọmọ Ọlọhun, ọmọ Ọlọhun, uhn Producer mi n gbọ lọwọ, ah Ma ṣe pe mi ni bọlọ, see my life's so settled Aroma cash out, no be say emi mo ṣiṣẹ ju Instablog don dey blog many things Say me puff-puff-puff anything Lati day one, mo l'enemies Ọmọ ẹru kan, o fẹ ri mi Wọn ni iru mi, ki ni mo mu? Don Peri' ni L'adugbo mi, wọn bẹri ni No pretending, my Camaro, hot engine Yeah-yeah, yeah (uhn-uhn, ooh) Ninu aiye, ninu aiye Ọmọ Ọlọhun, wọn mọ mi Ma l'owo Dangote Gbẹdu to m'ori bombay Ninu aye, ninu aye Ọmọ Ọlọhun, wọn mọ mi Ma l'owo Dangote Gbẹdu to m'ori wọ'le Oh-ay-ay, ay-ah Them be dey ask, "Bawo lo ṣe n ṣe?" Ah-whoa, whoa-whoa Ko mọ pe, ko mọ, ah Boys them para, wọn o ṣere, yeah-yeah-yeah When I play less, no be say I'm brainless, yeah Instablog don dey blog many things Say me puff-puff-puff anything Lati day one, mo l'enemies Ọmọ ẹru kan, o fẹ ri mi Wọn ni iru mi, ki ni mo mu? Don Peri' ni L'adugbo mi, wọn bẹri ni No pretending, my Camaro, hot engine Yeah-yeah, yeah (uhn-uhn, ooh) Ninu aiye, ninu aiye Ọmọ Ọlọhun, wọn mọ mi Ma l'owo Dangote Gbẹdu to m'ori bombay Ninu aye, ninu aye Ọmọ Ọlọhun, wọn mọ mi Ma l'owo Dangote Gbẹdu to m'ori wọ'le Mbolo, mbolo (M-M-Murderer) Maami oh, maami oh Ubāmi me, kamala tō-oh, ma-ma pariwo (uhn-uhn) Mbolo, mbolo Daddy oh, daddy oh Ubāmi me, kamala tō-oh, ma-ma pariwo