Oba Mi De
Ty Bello & Tope Alabi
4:49Ore mi ti ki n se ore awon ota mi eeh eeh Awa gbe o ga Oluhun ko gun orun a jo si odumare opa tinrin kan le Awa gbe o ga Ojo mini mini ti n j’ara o de yan orun wa wa wa ki igba o pa da bo Awa gbe o ga Isale ale oru oru ikawo re lo wa Awa gbe o ga Iyin re lo da wa fun olorun Iyin re lo da wa fun olodumare Iko ko orun owo lo wa, ibi kan lo n gbe Iyin re ko ni tan lenu wa Awa gbe o ga Awa gbe o ga Awa gbe o ga Awa gbe o ga Awa gbe o ga Awa ni iran ti n s’aferi re o Awa gbe o ga Awa gbe o ga o Awa gbe o ga Agbara lo fi na aye ja lati salu orun wa’ye Owo re lo fi ina orun ja o po ko ja awon okun Iyin re ko ni tan lenu wa Iyin re ko ni tan lenu wa Awa gbe o ga Awa gbe o ga o Awa gbe o ga Awa gbe o ga o Awa gbe o ga Awa ni iran ti n s’aferi re o Awa gbe o ga Awa gbe o ga o Awa gbe o ga Ore mi ti ki n se ore awon ota mi eeh eeh Oluhun ko gun orun a jo si odumare opa tinrin kan le Ojo mini mini ti n j’ara o de yan orun wa wa wa ki igba o pada bo Isale ale oru oru ikawo re lo wa Pata pata ologo to n dan gbirin gbirin gbirin gbirin gbirin Didan ninu ogo ewa Isaju o orun Awa gbe o ga Awa ni iran ti n s’aferi re o Awa gbe o ga Awa ni iran ti n s’aferi re o Awa gbe o ga O ba ni mule ma da ni olowo ori aye Awa gbe o ga A a a wa gbe o o o Awa gbe o ga A gbe o ga o A pe o a pe o Awa gbe o ga Awa gbe o ga oooooo Awa gbe o ga Ore mi ti ki n se ore awon ota mi eeh eeh Oluhun ko gun orun a jo si odumare opa tinrin kan le Ojo mini mini ti n j’ara o de yan orun wa wa wa ki igba o pada bo Isale ale oru oru ikawo re lo wa Pata pata ologo to n dan gbirin gbirin gbirin gbirin gbirin Didan ninu ogo ewa isaju o orun Iyin re lo da wa fun olorun Iyin re lo da wa fun olodumare Iyin re ko ni tan lenu wa Awa gbe o ga