Omo Ope (Feat. Olamide)
Asake
2:47J'ọ mọ (It's Kel-P Vibes) (Whoo-ooh) Mo ti pe Paso Jẹ n na'wo yẹn ko to ku wazo Is it me or the Henny, or maybe na the Azul? That booty look like a place they told me not to go They told me not to go, they told me not to go Ọmọ, na things wey go kill me, me, I wan dey do Now put it down l'ori table, ko wo bo ṣe to Now put it down l'ori table, ko wo bo ṣe to Ọmọ, ṣo ri bo ṣe to? Mo ti pe Paso Jẹ n na'wo yẹn ko to ku wazo Is it me or the Henny, or maybe na the Azul? That booty look like a place they told me not to go They told me not to go, they told me not to go Ọmọ, na things wey go kill me, me, I wan dey do Now put it down l'ori table, ki n wo bo ṣe to Now put it down l'ori table, ki n wo bo ṣe to Ọmọ, ṣo ri bo ṣe to? K'ọn ma ba mi sọ o Ṣebi mo ti sọ pe k'ọn ma ba mi ṣe o Ọmọ, Paso ni mi gan-an, ọrọbọkibọ o Wọn ti fẹ lọ mu Pepsi mi, ọrọbọkibọ o Mi o gba o, wọn ni, "Mo n bọ o" Mo saare fo fence, k'ọn to yọ'ju o Mo dẹ fẹ ko t'ẹti e, ko gbọ o (gbogbo rederede) Bẹ ṣe ta si mi, mo gbo o, ah Ṣẹ gbọ o? Eh, ani, ṣẹ gbọ o? Ah Anybody wey go try me, ko gbọ o, ah Ara kan mi bo ṣe n wo mi, o le, o wa To ba de'bi, wọn ma gba ẹ l'oju, bo ṣe wa Debi toti naa Ani, wọn n bẹ (wọn n bẹ, wọn n bẹ) Ma da wọn l'ohun, wọn n be (ma da wọn l'ohun, wọn n be) T'ọn ba ri mi o, mo n ṣa'na, mo n dan T'ọn ba tun mu wa l'ori street, wọn a ba mi nibẹ Hm-mm, mm Mo ti pe Paso Jẹ n na'wo yẹn ko to ku wazo Is it me or the Henny, or maybe na the Azul? That booty look like a place they told me not to go They told me not to go, they told me not to go Ọmọ, na things wey go kill me, me, I wan dey do Now put it down l'ori table, ko wo bo ṣe to Now put it down l'ori table, ko wo bo ṣe to Ọmọ, ṣo ri bo ṣe to? Ọmọ, na the things me I want to do Na shima wey go kill me I want to do (kill me) Na the yansh wey go wound me I want to do (wound me I want to do) I'm sippin' on 1942, ay-ay (1942, whoa) And they ain't got nothin' on me, ay-ay Stop playin Wande, o wa bi ṣere Emi ọba orin, t'ọn ba ri mi, ay-ay They can't fuck with me Debi titori naa Ani, wọn n bẹ (wọn n bẹ, wọn n bẹ) Ma da wọn l'ohun, wọn n be (ma da wọn l'ohun, wọn n be) T'ọn ba ri mi o, mo n ṣa'na, mo n dan T'ọn ba tun mu wa l'ori street, wọn a ba mi nibẹ Mo ti pe Paso Jẹ n na'wo yẹn ko to ku wazo Is it me or the Henny, or maybe na the Azul? That booty look like a place they told me not to go They told me not to go, they told me not to go Ọmọ, na things wey go kill me, me, I wan dey do Now put it down l'ori table, ko wo bo ṣe to Now put it down l'ori table, ko wo bo ṣe to Ọmọ, ṣo ri bo ṣe to? Mo ti pe Paso Jẹ n na'wo yẹn ko to ku wazo Is it me or the Henny, or maybe na the Azul? That booty look like a place they told me not to go They told me not to go, they told me not to go Ọmọ, na things wey go kill me, me, I wan dey do Now put it down l'ori table, ki n wo bo ṣe to Now put it down l'ori table, ki n wo bo ṣe to Ọmọ, ṣo ri bo ṣe to?