Laifoya L'Apa Jesu
Bode Afolabi
3:041.Fun anu to po b’iyanrin, Ti mo ngba l’ ojumo; Lati’odo Jesu Oluwa, Kil’ emi o fi fun? 2. Kini ngo fi fun Oluwa, Lat’inu okan mi? Ese ti ba gbogbo re je, Ko tile jamo nkan. 3. Eyi l’ohun t’emi o se, F’ohun t’O se fun mi; Em’o mu ago igbala, Ngo kepe Olorun. 4. Eyi l’ope ti mo le da, Emi osi, are; Em’o ma soro ebun Re, Ngo si ma bere si. 5. Emi ko le sin b’ o ti to, Nko n’ise kan to pe; Sugbon em’o sogo yi pe, Gbese ope mi po