Jehovah Alagbara
Oluseyi Solagbade
4:25
(Intro)
(chorus)
Idemija nigba timo rii baba mio
Ayomi kun nigba timo rii baba mio
Araa milee nilee eyi si dera o
ogun tii seo nigba timoo rii baba
(1st verse)
JIMAHTAH Eri olola moseba arugbo ojo o
IRAH JAHMAH JAHRIBAH AA IRAHJAMAH
Eyin ogun orun topo nipa atagbara moni esokale
wa o ewa gborin ko lee numi o
Tori abiamo iigbekun omo re koma takiji o
babaa mi gbo mi o MICAHILI
FIFAH SEH ELI SALA SALI ASA LASA SAFE SALI
TILA FELI ASA LI
(chorus)
Idemija nigba timo rii baba mio
Ayomi kun nigba timo rii baba mio
Araa milee nilee eyi si dera o
Ogun tii seo nigba timoo rii baba
(2nd verse)
YARAH SARAH o Etan mole ja de o
Awan orun soro ogo Olorun ofurufu fise owo re
hon aaa ojo de ojo fimo jade
oru de oru fii mohon kosi ibi kan o tabi ede kan
ni biti akogbo irowan o
irowan lagbogbo aye ja o nibe lati gbe pago
fun Orun Michahili FIFAH SE ELI SALA SALI
ASA LASA SAFE E SAALI TILA FELI ASA LI
(chorus)
Idemija nigba timo rii baba mio
Ayomi kun nigba timo rii baba mio
Araa milee nilee eyi si dera o
Ogun tii seo nigba timoo rii baba
(hook)
Molo wole de o
(chorus)
Omo alade alafi a oma wolede
Kiniwun eya judah atobi julo Olugbala araye
(hook)
Molo wole de o
(chorus)
Omo alade alafi a oma wolede
Kiniwun eya judah atobi julo Olugbala araye
(hook)
RUSULLAR KAREEM RABBIL ALAMIN
Epago temi fun mi e